Percy's Couture

A mu ni dara, a won lo n woso lo n woso to dara
A mu ni dara, a won lo n ranso lo n ranso asiko
Aso asiko owo won lo wa
Percy's couture se wa loge

Ibikunle omo Adegokun
Alase percy's couture
E wa wa de ikeja, a tiko shopping complex
Oririsi la n ran
Adupe fun eledumare, adupe fun olorun oba
Awoyomi e siwaju, oko fumi ni elite
Ore kai omo adebisi, oko bola baby mi o ma se o
E bami toju milayo aya hyper e ba mi ki

A mu ni dara, awon lo n ranso lo n ranso to dara
A mu ni dara, a won lo n ranso lo n ranso asiko
Aso asiko owo won lo wa
Percy's couture se wa loge

Percy's couture pelu maste dollar
Aso ta won mejeji ran, de be ni o
Ma bami toju Adeola omo Faduroti
Oko Jumoke Ajibi ko ma ba mi ki
Ija sele eni a te ka omele ni ewele
Maste dollar designer, Isaga lo wa ni surulere o
Awo temi Ayinde mo ko na
Maste o se
Percy's couture pelu maste dollar
Aso ta won mejeji ran, de be ni o
Maste doll, maste doll, maste doll, maste doll
O ran so, o ran so, o ran so, o ran so

Percy's couture pelu maste dollar
Aso ta won mejeji ran, de be ni o

Akanni la fi ba n gbo, Olorun wa n bi o
Oko Wakilat, oko Laide
Ola baba wa Kingsley o
Alaga national ni Lagos state
Ma bami toju, oluomo Ayinde musului mi
Eyan ti toju dini omo agbede
Mo ki gbogbo national
National lapapo patapata
Ogun a ma so wa ona eni ye
Ma gbo bi mo se n wi
Walimu Zainab omo Dekunle, Akanbi
Ko to ju Muda Zainab mi omo Tijani kekere
Omo Sheu meni meni
Oko Barakamitu baba Egunjobi
Oko Ramota Layi Fola Awiye
Ana Monsuratu mi, omo oluwo nla
Nle o omo orogun ejiga
Eyan Ajabi Taofiki mi oko Kudiowo
Ana Muritala mi l'Epe
Aduni Rashida mo ki e sile (sile)
Oluwakemi jinke mi o se
Alase Jinke petroleum
Omo olomu ape omo lara gogo nle omo asigba lomo jomu jomu
Ore Suliatu mi Aduni aya Malo
Awon oyinbo mi leko, o seun mi
Mo ma ki e ki e Aduni Monsura
Omo ni e o yi ka model egunjobi
Oyinbo alaso, awon small
Afola n le, Eyan Lateefu Shittu mi o seun o
Olayinka omo Titilola, oyinbo ki e nle
Oko kemi baba Yinka Junior
Baba Adewale baba Adebola
Omo onife mure omo gba bi owo emo
Hun gbagbe Kunle, Kunle omo teni tila
Alase worldwide, oko Folakemi re bi ti omo Aluko
Wo baba Flavour, ife ni le odudua o seun

Percy's couture pelu maste dollar
Aso ta won mejeji ran, de be ni o



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link