Yes and Amen

Amin ase ida a lamo o
Eni ti o ni a padanu
Iba o to to olu Imo o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Amin aseda

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan (ko ni nkankan)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
E ko ni nkankan o

Mo wa ri foba to ni di da aiye
Ibare mare e, oni gbede orun
Iwo to ni gbogbo aiye ni ikawo
Bo ti doyi kato
Iba oni mo to ga ju, eh-eh
Baba ni baba se
Amin ase ida mo gbe ba fun
Amin ase ida la mo o

Eni ti o ni o ke, eni ti o ni a padanu, adanu nla lo pa laye, lorun
Iba o toto olu imo
A ton ton to, mo ri ba, mori ba o
Eni ti o ni o ko ni nkankan, ko ni nkankan
Eni ti o ni o ko ni nkankan o
E ma ni penre labo, eni ti o ni o, ko ni nkankan
Ko ni kini nkan lagbon, eni ti o ni o, ko ni nkankan o
O tan fun laiye lorun o, eni ti o ni o

Ko ni nkankan, o da okun, O da oosa
Alara to fi omi se osho, iwo to mo ibi eja gba do odo
Majemu to bu ko ja okun
Iyanrin te ka aiye, o da okunkun biri mu
Oga imole, oju orun o ni ilekun o
Ogbe bi mejeeji, lai rin irin ajo, o mu eda gba inu eda waiye
Ibi emi ngba lo ba, eni kan o mo, ajulo o, eni ti o wa o
Ko le mo nkankan, eni ti o wa ke o

Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Ko ri nkankan o o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
Afoju san ju oni to hun lo mo gba
Eni ti o ni o (e-e), ko ni nkankan, ko ni nkankan
Eni ti o ni o (e-e), ko ni nkankan

Majemu alai lepin n lo je, ijinle alaile tun wo
Irawo nyo lailai lo nka beni, osupa nse atokun to ba dale beni o
Ibi gbogbo la n ti mi ri beni, o to lo fara da orun saiye beni o
O se ojo otun so da eran beni
Osuwon bi oye, otun sotutu beni o
Eranko Igbo won lo su a beni
Eweko, ewebe igi iyen o se sawa ri na

Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o
Eni ti o ri se e, ko ri nkan
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan
Ko da ko ri ra e pa be ni
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o-o
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan

Ose mi da bi ohun, opin mi ni ipin, ti ko Jo ti eni keji
Mi o la le hu, emi ni ami aseda latorun
Adagbeyin ni mi o wa fi mi joba
Ohun gbogbo ti o ti ko da, odami ofunmi ni re
Emi ni beeni, ase olodumare ni, amin lohun, emi lami
Ayanmo ogo, ogun mi ni
Eda emi lo fi se ranse mi
Akori Iran mi, oju ogo re ni

Mo ni imi ye re ninu
Eni o ri mi, ko ri nkankan e, eni ti o ri mi
Ko ri nkankan, eni ti o ri mi e
Ko ri se olorun wo e, eni ti o ri mi ke, ko ri nkan
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan o, e o foju
Eni ti o ri mi, ko ri se Olorun wo
Ko ri Olodumare, oda mi bi ohun ni
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan

Eni ti o ri mi, ko ri se Olorun wo, o
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan o
Eni ti o ri mi, eni ti o ri mi, ko ri se Olorun, eni ti o ri pa, aje ko ri nkankan
Eni ti o ri mi ko ri nkankan

Ami lawa je, si iwo amin
Beni ire loje ki aiye wa o

Olorun la min
Amin lon famin wa han
Aiye, atorun lamin yen o
Aseda ni amin
Oro re lo je ki a ma wa
Olorun lamin, Olorun lamin

To ba se amin, Olorun lo se (amin, amin, amin), to ba so pe amin Olorun (amin)
Amin Olorun ni (amin), amin ori wa, amin irin ajo (amin), amin ati waye
Amin ati gbe aye (amin), amin ati pada, amin gbogbo e (amin), amin ati ye e (amin)
Amin ati se rere (amin), amin ati goke (amin), amin ati bo lowo ogun (amin)
Amin ati di eni nla (amin), amin lami ori wa (amin), ese amin o, amin
Amin loruko re aseda (amin), amin loruko re aseda (amin)
Amin ni mo se kemi bale ye (amin), amin ni mo se kin le goke (amin)
Amin ni mo se kappa ota ma kami (amin), amin ni mo se kin le din la (amin)
Amin ni mo se kin le pada (amin), amin ni mo se kin le ba joba (amin)
Amin ni mo se si Olodumare (amin), mo sope yes, mo sope amen (amin), mo sope yes, mo sope amen



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link