Eba Mi Ki

Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Ọbà tó ṣé mi lóore
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Obà tó ṣé mi láàánú o

Ẹ má bá mi ki oo ooo
Ẹ má bá mi ki aa aha
Ọbà tó ṣé mi lóore aaee
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Obà tó ṣé mi láàánú ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi kí ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi ki aaaa
Ọbà tó ṣé mi lóore (ọbà tó ṣé mi lóore)
Ẹ má bá mi ki ooo (oo)
Ẹ má bá mi ki Aaaa (aaa)
Obà tó ṣé mi láàánú ó (ọbà tó ṣé mi láàánú)

I know I don't deserve the love you show to me
Kínní mó lé físón o
Áfí ọpẹ eee
Òṣèto ayémi dáara dáara o
Òfimi dáara irè
Ọ'nà ará lógbà, oyè kín kí

Oh what kind of faithfulness is this?
O Lord, Òjé olódodo sìmi tinú tèyin o
Olóre mi, àlánú mi
Tí kìí sú o
Mọọma dúpẹ' ọrẹ, am grateful o

Ẹ má bá mi ki ooo (am grateful)
Ẹ má bá mi ki Aaaa (mọ wá dúpẹ' ọrẹ ni)
Ọbà tó ṣé mi lóore (eèrò ẹ bá ń kí, ẹ bá ń kí)
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki Aaaa (ẹ má bá mi kí)
Obà tó ṣé mi láàánú o (ọbà tó wò mí sún sún tó ṣe mí láàánú)

Your mercy is what am dwelling into
Since I was in my mother's womb
Olúbi tó ṣe dá tó fi ẹsẹmi lélẹ'
You have been my shield my shelter and light
Iwó loto mi bó o
Pàánpe ọ'nà àyè koje ko mú mi
Morín lafoni foji kòtò gẹ'gẹ' rẹ oshomi your bound with me is love
Olùsọ ẹ'mí àti àyè tí mòni
Aké ni agẹ' ni un ó ròyìn re fara yé ki wọn bá mi kí o

Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Ọbà tó ṣé mi lóore
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Obà tó ṣé mi láàánú o

Botiwu kò gùn pòóto
Botiwu kí ọ'tá pòóto
Ọlọ'run jẹ' olódodo o
Bowu ósá kò máa sá
Bowu òkun kò má kùn
Òdodo Ọlọ'run yòò wá títí láìlai
Botiwu kò na jìn tó
Botiwu kò kédá tó
Ọlọ'run jẹ' olódodo o
Botiwu ké kun pòóto
Botiwu kẹrin pòóto
Òdòdó rẹ Ọlọ'run yíò wa titilia
Òjé olódodo
Òdòdó rẹ ko má lópin
Òjé ọlọ títọ
Kí máa se èké bi ènìyàn o
Ọ'rọ' tó bá tẹnu re jáde òdòdó ni
O gbé ọ'rọ' rẹ gaju orúkọ àrà rè lo o

Ẹ má bá mi ki oo ooo
Ẹ má bá mi ki aa aha
Ọbà tó ṣé mi lóore aaee
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Obà tó ṣé mi láàánú ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi kí ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi ki aaaa
Ọbà tó ṣé mi lóore (ọbà tó ṣé mi lóore)
Ẹ má bá mi ki ooo (oo)
Ẹ má bá mi ki Aaaa (aaa)
Obà tó ṣé mi láàánú ó (ọbà tó ṣé mi láàánú)

Kosi ìlà kọjá tio mó Ìjì ń jà lóko Jésù sún òróri
Òjó gbó Lórí Sárà
Pelina ń fi Hannah ṣé rin-rin
Botiwu kó ọjọ' pe tó
Kénì yàn gbàgbé re to
Lati nu agbo eran
Amu Dafidi kékeré kò wá jó bá Òjé olódodo Òdodo re kò má lópin
Òjé ọlọ títọ koma ise ènìyàn
Kólé gbàgbé láì
Ọ'rọ' toba tẹnu re jáde
Odoni ogbe ọ'rọ' rẹ ga ju orúkọ ara rẹ lo

Ẹ má bá mi ki oo ooo
Ẹ má bá mi ki aa aha
Ọbà tó ṣé mi lóore aaee
Ẹ má bá mi ki ooo
Ẹ má bá mi ki aaaa
Obà tó ṣé mi láàánú ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi kí ó (Ẹ má bá mi kí)
Ẹ má bá mi ki aaaa
Ọbà tó ṣé mi lóore (ọbà tó ṣé mi lóore)
Ẹ má bá mi ki ooo (oo)
Ẹ má bá mi ki Aaaa (aaa)
Obà tó ṣé mi láàánú ó (ọbà tó ṣé mi láàánú)



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link