Iyin Ye O

Iyin yeah o
Oba to femi
Ogo ye o
Oba to femi
Kabiesi re o
Iyin ye o
Oba to femi
Ogo ye o
Kabiesi re o eh
Ogba mi lowo iku
Ore mi otito
Ofi keke ogun aye mi jona
Olu gbe ja mi ni
Ko se ni to le se o; afi wo
Kabiesi re o eh
Mo juba mo fori ba le fo ba
Iwo ni ologo julo

O fo gbogbo ilekun ide aba wole si ogo mi
Ojo gbogbo jankari wo
Emi odi won teriba
Okuta ti awon mole ko
Wadi pataki igun aye
Owo anu re to fi gba mi oga
Mose ba fele yinju ife

Ona mi la mo ri ore ofe
La to do Aseda
Owo olonde ge so nu
Ohun ija won lo nu loro
Emi leri emi lo go
Asotele ni mo je
Majemu Olorun fohun la ye mi
Mo fiyin fa duro ti ni gbangba
Emi leni ti Oluwa fe gan
Ti ati da lare



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link