Baba Orun

Great and mighty King
Glorious and wonderful
All things are made perfect in your holy name
Baba orun e
Baba orun Eledua Eledua

Baba orun Eledua mo se ba re
Baba orun Eledua mo se ba re
Baba orun Eledua mo se ba re
Baba orun Eledua mo se ba re

Ope ni fun Oluwa
Iyin lo ye Jesu baba ti wa
Ope ni fun Oluwa
You deserve all the glory
You deserve all the honour Jesus

Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f'oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f'oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f'oba je
Moriba moriba moriba Baba mi Oba nla tin f'oba je
Ogo ni f'oruko re mo yin o logo
Ari ro ala mo se ba fun o

Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
(Baba Orun) Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
(Baba Orun) Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
Baba orun Eledua mo se ba re
Baba orun o Eledua mo se ba re
Baba orun o oo Eledua mo se ba re
Baba orun Eledua mo se ba re

Ogbamu gbamu oju orun o se gbamu
Olowogbogboro Kabiyesi iba re
Opo to so aiye ro baba mi
Ooo iba o
Ogbamu gbamu oju orun o se gbamu
Olowogbogboro Kabiyesi iba re
Opo to so aiye ro baba mi
You deserve all the glory
You deserve all the honour Jesus

Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f'oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f'oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f'oba je
Moriba moriba moriba e Baba mi Oba nla tin f'oba je
Ogo ni f'oruko re mo yin o logo
Ari ro ala mo se ba fun o

Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
(Iku gbo oruko re o wo gbo, arun gbo oruko re o sa wole)
Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
(Alapanla to sole aiye ro, Ogo lo ye o oo) Gbani gbani t'aiye saya ajuba re Olorun akoda aiye
(Ogo lo ye o oo)
(Baba Orun) Eledua mo se ba re
(Baba Orun) Eledua mo se ba re
(Oba mimo, ton wo mimo, ton se mimo) Eledua mo se ba re
(Ton je mimo, Emi mimo) Eledua mo se ba re
(Mimo mimo l'oruko re) Eledua mo se ba re
Eledua (King of king Lord of lords) Eledua
(Mo se ba re)

Credits
Writer(s): Anthonia Afuape
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link