Oba

Rejoice rejoice rejoice in Him
For he is the everlasting King
Rejoice rejoice rejoice in Him
For he reigns forevermore
Our Father whom remains the same
He was, and is, and is to come
So place your hope on him who reigns
Forever on his throne

Olorun Oba imole
Ko s'eni to da bi re
Egbe ga oba to dara
Nitori anu re po
Gbo omo ko si teti
Wakati ire l'eyi
Gbe wa wo Oba alanu
Akole se lai ri o

Oluda aiye Olorun aseda orun
Iwo ni mo mo, iwo ni mo gb'oju le, iwo ni mo f'eyin ti
Awa o ri o, sugbon a rise re royal majesty Oba
Oba gbogbo eda, Oba awon oba
There is no one like you Lord

Olorun Oba imole
Ko s'eni to da bi re
Egbe ga oba to dara
Nitori anu re po
Gbo omo ko si teti
Wakati ire l'eyi
Gbe wa wo Oba alanu
Akole se lai ri o

Oo ooooo ooooo
Ko s'eni t'oda bi re
Olorun mi o



Credits
Writer(s): Anthonia Afuape
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link