Oba (Intro)

Eyin l'Oba ano oooooo
Eyin l'Oba oni ooooooo
Oba titi aiyeraya
Oba ti ko ni pe kun

Emo ibi t'emu mi lo
Emo eto aiye mi
Je ki ife re ni kan se ninu aiye mi
Ero e nikan ni ko bori

Emo ibi t'emu mi lo
Emo eto aiye mi
Je ki ife re ni kan se ninu aiye mi
Ero e nikan ni ko bori



Credits
Writer(s): Anthonia Afuape
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link