Kosun Tadie

Wan ran 'mọ lọ'ja
Ko lo r'ori ọkà oni nọyin wa
Wan ran 'mọ lọ'ja
Ko lo r'ori ọkà oni nọyin wa

Itun meje, at'arẹ meje pẹlu adere meje
Wan wa gun pọ, wan ko m'ọṣẹ dudu
Wan wa gbefun padi ẹ
Padi Ọdẹnson

Wan wa gbefun padi ẹ
(Padi Ọdẹnson)
Wan wa gbefun padi ẹ
(Padi Ọdẹnson)

Oṣika ma ṣe'ka mọ o
(Ika a p'oni'ka o)
Oṣika ma ṣe'ka mọ o
(Ika a p'oni'ka o)
Oṣika ma ṣe'ka mọ o
(Ika a p'oni'ka o)
Oṣika ma ṣe'ka mọ o
(Ika a p'oni'ka o)

Ika a p'oni'ka o
(Ika a p'oni'ka o)

Ika a p'oni'ka o
(Rere a b'ẹni rere)
Ika a p'oni'ka o (hee)
(Rere a b'ẹni rere)

Odaju
Ẹni gbẹkun gba laye
Aya rẹ a jẹ, ọmọ rẹ a jẹ
Oun naa a wẹwẹ sẹ



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link