Sunny Koni Ku

Koni ku o
Rọmọla Ofeṣe
Koni ku o
Sunny mi o ni ku o
Rọmọla Ofeṣe
Koni ku o
Tori gunugun kii ku s'ewe
O ṣe'wọ o
Ẹnikan ki ba alágẹmọ labẹ ewe
Bẹẹni, a kì ma rọ gidigba la lẹ odo

Koni ku sẹ
Rọmọla Ofeṣe
Koni ku o

Adìyẹ yo, adìyẹ pogun
Wan l'adiye ro p'ọmọ rẹ
Adìyẹ rọgbọn, adìyẹ pọgbọn
Wan l'adiye ro p'ọmọ rẹ
Wan binu gb'adiyẹ ta
Wan f'owo ra'wo
Awo y'ẹyin mẹfa
O fi pa kan ṣoṣo
Ọkan ṣoṣo girogiro
Ọkan ṣoṣo l'ẹrin n ṣe gbo
Ọkan ṣoṣo r'ẹfan ni sọdan
Ọkan ṣoṣo l'ajanaku nimi gbo kiji-kiji-kiji

Awa ti b'egun ja o
Aṣẹgun re'gungun
Ati b'ọrìṣà já o
Awa d'oriṣa kunlẹ bọ
Awọn agbejọ ra lo f'ọlọrun ọba
Bambaa ni baba n da

Ẹni t'ọlọrun ba ti dá
Ko ṣe f'arawe
Ko ṣe f'arawe
Bamba ni n baba da wa o
Ko ṣe f'arawe
Ẹni tí Ọlọrun ba ti dá n nkọ
Ko ṣe f'arawe
Gbamugbamu jigijigi
Ko ṣe f'arawe



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link