Rod Publicity

To ba fe polowo oja lona to ma mo wo wa
To ba fe polowo oja e lori newspapers
Agaga to ba fe lori Radio pẹlu television
To ba ti dé eko ko bere sketch and skreet
To ba ti dey sketch and skreet ko bere number forty
To ba ti dé bè o n la ti ri Rod publicity
Oga níwòn je
Rod publicity oga níwòn je
Rod publicity oga níwòn je
Remi raderoye o managing director ni
Rod publicity oga níwòn je
Idilolu Falaye creative director
Rod publicity oga níwòn je
Akin Davis public relations director
Rod publicity oga níwòn je
Rod publicity oga níwòn je
Rod publicity oga níwòn je
Eroya bami kalo sile olowo oja
Rod publicity oga níwòn je
Eroya bami kalo sile olowo oja
Rod publicity oga níwòn je
Rod publicity ooo
Oga ni won je
Rod publicity oga níwòn je
Rod publicity oga níwòn je eeeee



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link