Kajo Jijo Olomo

Okunrin abiro, obinrin abiye
Okunrin abiro, obinrin abiye
O so meji meji ko fun wa
Agan a t'owo alabosun
Kajo jijo olomo

Ijo olomo jelenke ni o (ah)
Jelenke (ah), jelenke ni o
Jelenke (ijo olomu), jelenke ni o
Jelenke (okulu mu ke), jelenke ni o
Jelenke (ke ba won jijo olomo), jelenke ni o
Jelenke (eni a b'imo a mujo), jelenke ni o
Jelenke (easy), jelenke ni o
Jelenke (ka bere mo'le ka f'ijo ha), jelenke ni o
Jelenke (ijo olomo), jelenke ni o
Jelenke (lulu si mi n'ibadi o jare), jelenke ni o
Jelenke

Check e, o wan be



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link