Enia Se Rere

Eniyan se rere
Eniyan se rere o
Eniyan se rere o
Eniyan se rere o
Bo ba se rere
Aye a ye o

Bo ba se rere
Orun re a suwon
Eniyan se rere o
Nitori ati sun o
Eniyan se rere o
Nitori ati sun o
Eniyan se rere o
Oju ola la n to
Eniyan se rere o
Ojo ola ni k'a ma ro
Eniyan se rere o

Kini ayo re nigba ti Jesu pe o?
Kini ayo re? Jowo so funmi
Kini ayo re nigba ti Jesu pe o?
O ayo, o ayo ni t'emi

Ayo, ayo ni t'emi
Ayo, ayo ni t'emi o
O ayo, o ayo ni t'emi



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link