Chief George Oyedele

Nawo nawo yato Si olowo
Bọwọ ba ti dé éje a nawo
Nawo nawo yato Si olowo
Bọwọ ba ti dé éje a nawo
Ẹjẹ a f'owo dabira
Eni to lowo lóba ereke
Ẹjẹ a f'owo dabira
Eni to lowo lóba ereke

Ore bimo ba lowo ma nawo
Ma fi mo ebi mo ara
Ore bimo ba lowo ma nawo
Ma fi mo ebi mo ara
Ma ṣí tun wa bebe fún ohun mẹrin ototo
To dile ayé mu
Kilo ohun mẹrin tó di ayé mu
É salaye fún mi kin gbo

Amo ohun ti yẹ ní sí niwipe
Olowo a jo'gun owo, yes
A jo'gun ìyí, atun di gbajumo lóde
Asiri won o ni tu
Tori asiri eko, koma ni tu loju ewe
Asiri ologini, kii tu loju ekute
Ewoni towo, àṣẹ edumare ni

Amo ohun ti yẹ ní sí niwipe
Olowo a jo'gun owo, yes
A jo'gun ìyí, atun di gbajumo lóde
Asiri won o ni tu

Olowo to n nawo rẹ ma ṣe ba wi
Ayipada olowo, koma se di talaka lan tọrọ
Ayipada talaka, ko di olowo Lola loye
Tori bode ba ro se roya
Toba pa eran, ko ní fún enikan je l'ai l'ai
Iṣẹ l'ose da'se, owo o se da na
Iṣẹ l'ose da'se, owo o se dáná

B'ile ba san ni awo la n wo
Bi ọ Si san ni awo lan ri
B'ile ba san ni awo la n wo
Bi ọ Si san ni awo lan ri
Ewo enu ile, ewo enu oko
Ewọ George témi, omo oyedele
Máa rìn rìn gbeere máa dé bè
Gbamo iishabi o
Ma fese kan delẹ chief George
Omo Oyedele

Chief mayegun Iseyin, chief bagbile ikija
Labe olumo
Eba mi pawopo, kebami toju chief b'oba gun wa
Oke rona labẹ okuta, koda
Taba pe mi bagbile gbogbogbo
Koma buru rara
Oloye yin je oya meta po

Jagunlabi reti ekerin o jàre
Olowo ori oko adetoro, pupa yemi
Ọmọ tó gb'afe, adetoro ohun ni
Ogbokikikija, labẹ olumo
Adetoro pupa yemi, roloyinbo
Rẹ r'oko to gbafe, omo dacosta
Ni ijesha modu rapanada ti wa ni

Mama olarewaju, mama folasade
Mama olabosipo mi, chief Oladeinde ọmọ Oyedele
Ko se tọju alaja abiba omo togbafe beni rẹ
Ìyẹn ni mama oladapo, mama Olajide
Ọmọ alhaji tijani n'dabi labẹ olumo
Olowo ori oko oniyabobe
Ìyẹn ni mama ola ronke
Chief Olawole, ọmọ chief Samuel mi atata
Olakunle lakure, ile oloye
M'ekun m'aba bẹ ba ri chief George lode e

Ko pe meji rara, funfun ne ne loju agbo tori
Fìlà funfun, ewu funfun o
Shokoto funfun, bàtà funfun o
Ewu funfun, fìlà funfun ni o
Ọmọ nimi ni nigba kugba
Fìlà funfun, ewu funfun o
Shokoto funfun, bàtà funfun o



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link