Mobolaji Akanni (Intro)

Mobolaji Akannni oo
Akinkanju lo je ni bi ka korin to dun gbo si eti araye
Ajin bo n de ni e
Oko Alake
Omo ati idi ba obinrin ja denu denu
Omo Alakejobi ero Egba
Hun o si ma ki Baba e
Omo Alakejobi Ero Egba ti mo seyin oro ki n to se T'egun
Iwo l'omo hunda
Omo ile amo
Omo Oluwabi
Omo hunda o mo ana
Omo hunda o muti
Eni ba fun yin lomo le n se l'ore o
Akanni oo
Ma da kojokojo
Ere ti ya ooo



Credits
Writer(s): Mobolaji Oluwabi, Bolson Omobolaji, Adekundi Kosoko
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link