Emo (Kalankili)

Emo ti sele
Araye e wa wo emo lukutu pebe
Emo ti sele
Araye e wa wo emo lukutu pebe
Ole gba iyawo ole
Ole gba aso omuti
Omuti fun omo olowo ni oyun
Oro wa di oro adajo
Oro wa di
Ka la n kili
Ka la n kolo
Bi o ba pa mi mi oni fun e ni
Ona lo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Bi o ba pa mi mi oni fun e ni
Ona lo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Bi o ba pa mi mi oni fun e ni
Ona lo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Ka la n kili
Ka la n kolo

Won ni ko wa ro ti enu won
Ki won so
Ale ole ni Ole o se to
Ole ni omuti o buyi fun aso
Won ni ka farabale
Ki a gbo oun ti omuti fe so
Omuti gu fe
Ki o to soro

Oni otutu ni o le ohun de ile olowo
Oni ohun fe lo iba aso ni owo olowo
O ba de ile olowo
Omo olowo ti o ba ni ile
Oso
Oni Booda omuti
Booda Omuti

Booda omuti
Eniyan bo ni ni l'ara ju aso lo

Haa! Agbaya! Alailojuti
apooda
Emo ti sele
Araye e wa wo emo lukutu pebe
Emo ti sele
Araye e wa wo emo lukutu pebe
Ole gba iyawo ole
Ole gba aso omuti
Omuti fun omo olowo ni oyun
Oro wa di oro adajo
Oro wa di
Ka la n kili
Ka la n kolo
Bi o ba pa mi mi oni fun e ni
Ona lo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Bi o ba pa mi mi oni fun e ni
Ona lo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Bi o ba pa mi mi oni fun e ni
Ona lo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Ka la n kili
Ka la n kolo
Ka la n kili
Ka la n kolo



Credits
Writer(s): Justice Amadichukwu, Mobolaji Oluwabi, Adekunle Kamal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link