Wadomi

Bad boy mo
Bad
Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání
Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání

Everyday na yatayoto
Ó ta l'ẹ'nu bi átá rodo
From a one night stand
Ni ọmọ bá di Mario
Come dey go your house
She tell me no no

Wádómi wádómi
Wádómi ni mo sọ' fún ẹ
O wá fẹ' wá d'ìyawó lé mí
Wádómi ni mo sọ' fún ẹ
O fẹ' ma lo kàyàmátà fún mi
Má ṣe mí bẹ'ẹ yẹn
O fẹ' ma lo jàrúmà fún mi
Má ṣe mí bẹ'ẹ yẹn

Ọpẹ'lọpẹ' Jesù
Ọpẹ'lọpẹ' mummy mi
T'ó ń ṣ'àdúrà dédé
Èmi náà mo ma ti di
Mobọ'lájí Afọpátá ṣá

Èmi náà mo ma ti di
Mobọ'lájí abáyàkú Ọkùnrin
Èmi náà mo ma ti di

Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó mà fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání
Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání
Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó ma fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání
Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó ma fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání

Wá dó mi
Ó f'ọsọ
Wá dó mi
Ó bẹ'rẹ' sí ní tún'lé ṣe
Wá dó mi
Ó dá'ná
Wá dó mi
Ó fẹ' di ìyàwó ilé

Boy! Everyday na yatayoto
Ó ta l'ẹ'nu bi ata rodo
Ó b'ẹ'fọn l'ábàtá
Ó rò pé omi ló mu yó
She wants to turn number one of Big Daddy mo

Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó mà fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání
Àn'ọmọ yẹn fẹ' pa mí
Ó fẹ' sọ mí di gbẹ'rùdání
Wádómi wádómi
Wádómi ni mo sọ' fún ẹ
O wá fẹ' wá d'ìyawó lé mí
Wádómi ni mo sọ' fún ẹ
O fẹ' ma lo kàyàmátà fún mi
Má ṣe mí bẹ'ẹ yẹn
O fẹ' ma lo jàrúmà fún mi
Má ṣe mí bẹ'ẹ yẹn
Wádómi ni mo sọ' fún ẹ
O fẹ' ma lo kàyàmátà fún mi
Má ṣe mí bẹ'ẹ yẹn
O fẹ' ma lo jàrúmà fún mi
Má ṣe mí bẹ'ẹ yẹn



Credits
Writer(s): Mobolaji Oluwabi, Adekunle Olajide
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link