Mo Ni Ki Ndupe

Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni

Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni

Ágbáni lágbá tón ni
Òré olódodo ní
O'da bó bomi o
Ọtun pọn mí lé

Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Ko ni dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni

Kí gbọ'gbọ' ènìyàn gbé ga
Kí gbọ'gbọ' ẹ'niyàn gbé ga
Fun ẹnì tó kú nítorí wá o
Àpáta ayérayé
O jìyà nítorí wá
Nítorí gbọ'gbọ' ènìyàn ní
O'fẹ mi rẹ lèlé
Ẹ'jẹ' kí a dúpẹ' ọ'rẹ' tí Jésù se

Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni

Há! ẹgbẹ' mí é w'asia
Bí tí nfẹ lélẹ'
Ogún Jésù fèrè dé náà,
A'fere ségun (A'fere ṣẹ́gun)
D'odi mù, Ẹ'mí fẹrẹ dé (D'odi mù, Ẹ'mí fẹrẹ dé)
Beni Jésù nwi (Beni Jésù nwi)
Rán'dáhùn padà s'orun, pé (Rán'dáhùn padà s'orun, pé)
Àwa ọ dí mú (Àwa ọ dí mú)

Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni

Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni

Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Mo N'dúpẹ'
Mo kọ N'dúpẹ' ni
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ'
Fún ọrẹ tí Jésù ṣé
Mo kọ N'dúpẹ' ni



Credits
Writer(s): Apostle Ruben Agboola Jp
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link