Gbogbo E ni

Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Ìno ni ó jọ ọ'tá ilé Bàbá
Ìno ni ó jọ ọ'tá ilé Màmá tóbí mi (Ìno ni ó jọ ọ'tá ilé Màmá tóbí mi)
Nínú ayé
Ẹnì tó f'ẹrin bá mi jà (ohhhh, ohhh, ohh, oh)
Awọn ti wọn f'ẹrin dá mi lóró
Igbe rárà lára ké wọlé (ahhhh lára ké wọlé)
Jẹ'kó sunkún jáde láyé

Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Ó ṣe bí ọrẹ ṣé ibì, Ọ'tá mi lọ jẹ
Ó ṣe bí ènìyàn pàtàkì ó ní mi lara
Ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Jẹkó sunkún jáde láyé

Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọle
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ'tá mi bá fẹẹ yo kondo
Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ'tá mi bá fẹẹ yo kondo
Ọlọ́run máà ṣe gbà fún wọn
Awọn arògó bo gó je

Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ'tá mi bá fẹẹ yo kondo
Iwó ni ó bá mi lépa
B'ọ'tá mi bá fẹẹ yo kondo
Ọlọ́run máà ṣe gbà fún wọn
Awọn arògó bo gó je

Ọlọ́run mi
Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọlé (ahhhh lára ké wọle)
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin bá mi ja
Gbọ'gbọ' ẹni tó f'ẹrin dà mí lóró
Igbe rárà lára ńké wọlé
Jékọ́ sunkún jáde láyé

Jékọ́ sunkún jáde láyé (Jékọ́ sunkún jáde láyé)
Jékọ́ sunkún jáde láyé (Jékọ́ sunkún jáde láyé)
Àní ní lara ilẹ' Bàbá mi yẹn
Jẹkó sunkún jáde láyé (Jékọ́ sunkún jáde láyé)



Credits
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link