Wa Gbemi Ga
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọgbẹ Bàbá Jide gá
Ni ìgbà ayé tìrẹ
Ọgbẹ Bàbá Lola gá
Ni ìgbà ayé tìrẹ
Bàbá Adeboye ìwọ náà lọ sọ d'eni ńlá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọgbẹ Sólómọ́nì gá ó sọ d'oba
Ọlọ́run àgbáyé
Àwọn tó ti kọjá lọ
Ti ó ron s'àyè
Gbọ'gbọ' wọn ní wọn gbé ilẹ' ayé ṣe ìkan tó dára
Àsìkò mí nìyí ó Bàbá
Bá mi ṣe tèmi
Ọlọ́run àwọn tó t'gá (ahhh,ahh,ah)
Wá gbé mi náà gá
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró
Nínú igi
Nínú ìdààmú, ìwọ ló gbé mi dúró
Nínú igi
Nínú wàhálà, ìwọ lọ fún ní ìsinmi
Ọba t'kò fi mi silẹ nígbà kánkán ri
Ọlọ́run mí mọ gbé ó ga
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró
Oti Mósè lẹ'yìn
Ọtun bà mí ṣé
Oti David lẹ'yìn
Ọtun ṣé tèmi
Bàbá títí ayérayé ún ó má yín ó Ọlọ́run mí
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè (Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè)
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara tí (Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti)
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró (Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró)
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè (Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè)
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara tí (Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara tí)
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró (Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró)
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọgbẹ Bàbá Jide gá
Ni ìgbà ayé tìrẹ
Ọgbẹ Bàbá Lola gá
Ni ìgbà ayé tìrẹ
Bàbá Adeboye ìwọ náà lọ sọ d'eni ńlá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọgbẹ Sólómọ́nì gá ó sọ d'oba
Ọlọ́run àgbáyé
Àwọn tó ti kọjá lọ
Ti ó ron s'àyè
Gbọ'gbọ' wọn ní wọn gbé ilẹ' ayé ṣe ìkan tó dára
Àsìkò mí nìyí ó Bàbá
Bá mi ṣe tèmi
Ọlọ́run àwọn tó t'gá (ahhh,ahh,ah)
Wá gbé mi náà gá
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Ọlọ́run àwọn tó t'gá
Wá gbé mi náà gá ó
Lórí ìléde yí àti ní gbọ'gbọ' àgbáyé
Wá gbé mi náà gá ó
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró
Nínú igi
Nínú ìdààmú, ìwọ ló gbé mi dúró
Nínú igi
Nínú wàhálà, ìwọ lọ fún ní ìsinmi
Ọba t'kò fi mi silẹ nígbà kánkán ri
Ọlọ́run mí mọ gbé ó ga
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró
Oti Mósè lẹ'yìn
Ọtun bà mí ṣé
Oti David lẹ'yìn
Ọtun ṣé tèmi
Bàbá títí ayérayé ún ó má yín ó Ọlọ́run mí
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè (Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè)
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara tí (Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara ti)
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró (Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró)
Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè (Àti lẹ'yìn rẹ Elédùmarè)
Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara tí (Àti lẹ'yìn rẹ ato f'ara tí)
Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró (Àti lẹ'yìn rẹ lọ' mú ayé mi dúró)
Credits
Writer(s): Apostle Ruben Agboola Jp
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.