Beast & Peace
The winds will come to steal (Imọlẹ) the words I say
Huh
Uh, mo silent mood, but beast ni mi
Mo le cause violence, but still, peace ni mi
You don't have to hurt me, before you win
You don't have to kill somebody before you sin
O ṣa le browse, láì dẹ lo sub oh
O dẹ le go far without God oh
So mo duro t'Oluwa
So ko ki n ṣe iru wa
Even tọ ba fun yin labọ pẹlu spoon, ẹ le j'oju wa
Emi ma dẹ ti bad, lati aye la'dì-la'dì
Lati aye 1990 t'ọn lu beat pati-pati
Emi ti mo feel bad, mo dẹ ti feel good
Now mo feel better, Surulere bi Ojuelegba
Toripe mo wọ nnkan, wọn sọ pe mo wa on drug
Now mo wa on top, life mi o dẹ ni contour
Mo pa wọn ni Naija, o tun ba wọn ni London
Fun wọn ni KPK, Pọnmọ, Light-boy, wo, mo n ta'na
(Light-boy, mo n ta'na)
Uh, mummy mi ati daddy mi, wọn kan lọ n question mi
Wọn ni, "Ibo lo ti ri vibe yii, ṣe ọwọ demon ni?"
Awọn t'ọn senior mi, wọn bèrè, "Where you see money?"
Awọn ti mo julọ, wọn photocopy mi
First cashout mi, ọmọ iya, mo dẹ fi ra bazooka
Mo ko fun awọn sharp shooter
Ẹ ma binu t'ọn ba da si'ta
Tra-ta-ta-ta-ta-ta-ta fun awọn fake nigga
Awọn to fẹ shame mi, wo, emi wa shameless
Wọn fẹ stain white mi, but mo wa stainless
Awọn nigga t'ọn leave mi, wọn le ri realness
Toripe silence mi, no mean say na weakness
Shoutout si Iba J, Diarra, pẹlu Hayan
CY, Darosha, Prime Boy
Spending with my daddy, life mi wa splendid
Ologo, Zomo, TIA, Bella
(Chukwuchilly)
Soul
Mi ṣa mọ
Wọn ni iru ẹ
Iru ẹ t'ọn ni, ko ki n ṣe original
(Boombah)
O fẹ, o fẹ sun mọ mi
But, ko ki n ṣe oun gan-gan-an

Credits
Writer(s): Writer Unknown, Ilerioluwa Oladimeji
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.