Sabi

(No one is sleeker)

Wọn ni ki n wa baba to sabi
Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi
Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
Wọn ni ki n wa baba to sabi o (ehn-ehn, ehn)
Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi (uhn-uhn, uhn)
Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o

Uh, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan, o b'omi si garri
O wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun
Uh, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
O wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun

Huh, ki lo de o jere o?
Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o
Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o
Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o
Uh, wọn gun'yan mi kere o
Mo fíìmu wọn fọn fere o
Ninu aiye, mi o kere o
To ba de igboro, ko lọ béère o

Wọn ni ki n wa baba to sabi o
Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi
Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o
Wọn ni ki n wa baba to sabi o (ehn-ehn, ehn)
Ko wa w'ori mi, k'ọn to saasi (uhn-uhn, uhn)
Ki n ma ṣe ya'wo l'ọwọ Lati
Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ ko dabi o

Uh, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
O wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyàn Baba Fela ni, kẹ gba fun o
Huh, ọmọ ologo to sabi
Ọmọ gbera tan o, o b'omi si garri
O wọ Yankee o, Atlanta per roof
Èèyan Baba Fela ni, kẹ gba fun

Huh, ki lo de o jere o?
Mo ma j'aiye mi k'ọn to fun fere o
Uh, o ṣe o, o ṣe, o ṣe o jere o
Ti n ba ṣiṣẹ, ki n ma ko're oko de'le o
Uh, wọn gun'yan mi kere o
Mo fíìmu wọn fọn fere o
Ninu aye, mi o kere
To ba de igboro, ko lọ béèrè o

I will exalt You, Lord
For You have lifted me up
Has not let my foes to rejoice over me
(Timi Jay on the track)



Credits
Writer(s): Ayodele Ibukunoluwa, Promise Aloba
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link