Igba Eda
Igba teda ni
O lori ile
Igba eda yo koja lo
Bi ojiji
Eda yo pada
Sodo aseda
Eda yo jihin ohun to gbaye se
To ba npe wa nikan kan
To npe wa a a
Kama jihin ise wa
Ki lawa yio so
Igba aseda
Yo pew a fere de
Awon kan waye
Won patan ise tiiti
Won patan ise
Bi eni ti oni lo
Igba to ya
Aseda pe won
Awon kan wa
Won jadun aye titi
Won jadun aye
Bi eni ti oni lo
Nigba to ya
Aseda pe won
Ase boti wu
Kari ni aye
Lojo kan
A o je pe aseda
Igba teda ni
O lori ile
Igba eda yio koja lo
Bi ojiji
Eda yo pada
Sodo aseda
Eda yo jihin
Ohun to gbaye se
To ba npe wa ni kan kan
To npe wa a a
Kama jihin ise wa
Kilawa yo so
Igba aseda
Yo pe wa fere de
Ore mi wa
Faye re fun jesu
Asan laye
Imule mofo
Eni waye
Ti oni jesu ara
Toba pada
Ko ni le de ile
Mofi jesu lo o o
Faye re fun jesu
Ajo eda
Ofere dopin
Jesu npe o
Faye re fun jesu
Asan asan
Ladun aye je
Igba teda ni
O lori ile
Igba eda yo koja lo bi ojiji
Eda yo pada
Sodo aseda
Eda yo jihin
Ohun to gbaye se
To ba npe wa nikan kan
To npe wa a a
Taba njihin ise wa
Ki lawa yo so
Igba eda
Yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
O lori ile
Igba eda yo koja lo
Bi ojiji
Eda yo pada
Sodo aseda
Eda yo jihin ohun to gbaye se
To ba npe wa nikan kan
To npe wa a a
Kama jihin ise wa
Ki lawa yio so
Igba aseda
Yo pew a fere de
Awon kan waye
Won patan ise tiiti
Won patan ise
Bi eni ti oni lo
Igba to ya
Aseda pe won
Awon kan wa
Won jadun aye titi
Won jadun aye
Bi eni ti oni lo
Nigba to ya
Aseda pe won
Ase boti wu
Kari ni aye
Lojo kan
A o je pe aseda
Igba teda ni
O lori ile
Igba eda yio koja lo
Bi ojiji
Eda yo pada
Sodo aseda
Eda yo jihin
Ohun to gbaye se
To ba npe wa ni kan kan
To npe wa a a
Kama jihin ise wa
Kilawa yo so
Igba aseda
Yo pe wa fere de
Ore mi wa
Faye re fun jesu
Asan laye
Imule mofo
Eni waye
Ti oni jesu ara
Toba pada
Ko ni le de ile
Mofi jesu lo o o
Faye re fun jesu
Ajo eda
Ofere dopin
Jesu npe o
Faye re fun jesu
Asan asan
Ladun aye je
Igba teda ni
O lori ile
Igba eda yo koja lo bi ojiji
Eda yo pada
Sodo aseda
Eda yo jihin
Ohun to gbaye se
To ba npe wa nikan kan
To npe wa a a
Taba njihin ise wa
Ki lawa yo so
Igba eda
Yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
Igba eda yo pew a fere de
Credits
Writer(s): Segun Balogun
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.