Apata Mi

Kristi la pata mi
Kristi la pata mi
Kristu la pata mi
Ti mo duro le
Kristi la pata mi
Kristi la pata mi
Kristi la pata mi
Ti mo duro le
Biji nja lotun
Kristi la pata mi
Biji nja losi
Kristi la pata mi
Boku rawo kan
Soju orun
Kristi la pata mi
Toro ti so fun mi pe
Kemi ma se beru
Kristi la pata mi
Kristi la pata mi
Kristi la pata mi
Ti mo duro le
Oluwa mbe fun mi
Ki le niyan le se si
Apata nla
Lolorun ti mo ni
Oduro ti mi
Ombe lowo otun mi
Toro ti so fun mi pe
Kemi ma se baru
Kristi la pata mi
Kristi la pata mi
Kristi la pata mi
Ti mo duro le
Awon to gbeke laye
Awa won ako ri won mo
Awon to gbeke lorisa
Ikuna lo jasi funwon
Akoni eleru lolorun timo ni
Emi koni lati beru
Tori mo ngbe nu oluwa
Okan mi bale o
Okan mi bale o
Okan mi bale o
Emi ko ni lati beru
Tori mo ngbe nu oluwa
Okan mi bale o
Okan mi bale o
Okan mi bale o
Emi ko ni lati beru
Tori mo ngbe nu oluwa
Okan mi bale o
Okan mi bale o
Okan mi bale o
Emi koni lati beru
Tori mo ngbe nu oluwa
Okan mi bale
Okan mi bale o
Okan mi bale o
Emi ko ni lati beru
Tori mo ngbe nu oluwa



Credits
Writer(s): Segun Balogun
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link