Yara Eewo
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe lafin
Oba to ba wobe won kii lade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Eyi mumi ranti itan oba ilu kan
Uno sotan yi funwa o ki nto ma lo
Ilu aye gba jeje ilu olokiki
Ilu to gbajumo gidi ni abe orun
Lojo to joba aye gbo orun sim o
Bolorin ti nko laluduru nfon
Gbogbo ilu nfo fayo eyin ara mi
Yara eewo kan mbe laafin
Oba to ba wo be won kii lade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Bi won ti pari iwuye eyin ara mi
Awon oloye ilu won pejo saafin
Woni kabiesi o eni ye wa
Igba yin atu wa lara
Ikan ninu oloye ilu o lodide
Oni kabiesi moni oro lati so
Yara abalaye kan o mbe laafin
Oba alade kan won kii wobe
Oba to ba wobe won kii lade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Ojo afiyesi kan o eyin ara mi
Lojo afiyesi kan eyin eniyan
Olori pe kabiesi o laafin
Oni kabiesi moni oro lati so
Oro mi da lori yara eewo
Awon oloye ilu won ri wa lomode
Na se fogbon agba tan fi rewa je
Ati wipe mo lala o li oru ana
Mo rawon oloye ni yara eewo
Ohun oso iyebiye o na ko jade
Oba ba lori ohun gbogbo kabiesi
Yara eewo eni la o wo be
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe laafin
Oba to ba wobe won ki ilade lori mo
Eni ba dale awonnyen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Kabiesi gboro si olori lenu
Awon mejeji wo yara eewo
Bi won ti silekun ye o eyin eniyan
Isele kan sele ye o to jomi loju
Iji nla kan lo dide eyin ara mi
Iji gbe kabiesi odi nu igbo
Igba to de nu igbo eyin eniyan
Kosi ade lori mo kosi opa ase
Kosi rukere kosi si aso lorun
Eyi to jomi loju ni temi re e
Kabiesi boju weyin kori olori mo
Ase abani da won ki ibani wobe
Oba to ba wo be won ki ilade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Itan ti mo so o lo lasan o ara mi
Okuku ni tunmo nla kan o laye wa
Kabiesi ti mo wi o eyin eniyan
Eyi ni onigbagbo emi ati wo
Ade ti nmbe lori oba alade
Eyi ni igbala ti jesu fi fun wa
Irukere ye o pelu opa ase
Agbara emimimo ati isura re
Awon olye ilu ti nmbe laafin
Emimimo o ikan lo je
Bibeli mimo o iwe ayeraye
Atawon iranse olorun tooto
Ton toni sona ijoba olorun
Olori to pe kabiesi o laafin
Eyi ni ersn ara eyin eniyan
Eran ara ota ni solorun
Yara eewo ti nmbe laafin eyi ni ese
To nigbagbo di mowo
Kekere loje o tani nla ni
Ese npanirun onran ni sorun egbe
Inu igbo ti kabiesi bara re
Eyi nsapere ewu orun apaadi
Ese e loro eyin ara mi
Ese on pani oran ni soru egbe
Oba to ba wobe won ki ilade lori mo
Eni ba daleawon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Oro mi lo sodo onigbagbo
Gbogbo omo olorun ti nmbe laye
Awa ti gbeyi aye de ba o ara mi
Eje ka sora nitori ilu orun
Gbogbo iranse olorun o mo mbebe
Eyin woli ateyin baba wa
Eje ka pada leyin aye ese yi
Kamaba kabamo ni nilu orun
Oba to ba wo be won ki ilade lori mo
Eni ba dale awon yen kii dale
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe lafin
Oba to ba wobe won kii lade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Eyi mumi ranti itan oba ilu kan
Uno sotan yi funwa o ki nto ma lo
Ilu aye gba jeje ilu olokiki
Ilu to gbajumo gidi ni abe orun
Lojo to joba aye gbo orun sim o
Bolorin ti nko laluduru nfon
Gbogbo ilu nfo fayo eyin ara mi
Yara eewo kan mbe laafin
Oba to ba wo be won kii lade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Bi won ti pari iwuye eyin ara mi
Awon oloye ilu won pejo saafin
Woni kabiesi o eni ye wa
Igba yin atu wa lara
Ikan ninu oloye ilu o lodide
Oni kabiesi moni oro lati so
Yara abalaye kan o mbe laafin
Oba alade kan won kii wobe
Oba to ba wobe won kii lade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Ojo afiyesi kan o eyin ara mi
Lojo afiyesi kan eyin eniyan
Olori pe kabiesi o laafin
Oni kabiesi moni oro lati so
Oro mi da lori yara eewo
Awon oloye ilu won ri wa lomode
Na se fogbon agba tan fi rewa je
Ati wipe mo lala o li oru ana
Mo rawon oloye ni yara eewo
Ohun oso iyebiye o na ko jade
Oba ba lori ohun gbogbo kabiesi
Yara eewo eni la o wo be
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe laafin
Oba to ba wobe won ki ilade lori mo
Eni ba dale awonnyen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Kabiesi gboro si olori lenu
Awon mejeji wo yara eewo
Bi won ti silekun ye o eyin eniyan
Isele kan sele ye o to jomi loju
Iji nla kan lo dide eyin ara mi
Iji gbe kabiesi odi nu igbo
Igba to de nu igbo eyin eniyan
Kosi ade lori mo kosi opa ase
Kosi rukere kosi si aso lorun
Eyi to jomi loju ni temi re e
Kabiesi boju weyin kori olori mo
Ase abani da won ki ibani wobe
Oba to ba wo be won ki ilade lori mo
Eni ba dale awon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Itan ti mo so o lo lasan o ara mi
Okuku ni tunmo nla kan o laye wa
Kabiesi ti mo wi o eyin eniyan
Eyi ni onigbagbo emi ati wo
Ade ti nmbe lori oba alade
Eyi ni igbala ti jesu fi fun wa
Irukere ye o pelu opa ase
Agbara emimimo ati isura re
Awon olye ilu ti nmbe laafin
Emimimo o ikan lo je
Bibeli mimo o iwe ayeraye
Atawon iranse olorun tooto
Ton toni sona ijoba olorun
Olori to pe kabiesi o laafin
Eyi ni ersn ara eyin eniyan
Eran ara ota ni solorun
Yara eewo ti nmbe laafin eyi ni ese
To nigbagbo di mowo
Kekere loje o tani nla ni
Ese npanirun onran ni sorun egbe
Inu igbo ti kabiesi bara re
Eyi nsapere ewu orun apaadi
Ese e loro eyin ara mi
Ese on pani oran ni soru egbe
Oba to ba wobe won ki ilade lori mo
Eni ba daleawon yen ki idale
Yara eewo kan mbe laafin
Oro mi lo sodo onigbagbo
Gbogbo omo olorun ti nmbe laye
Awa ti gbeyi aye de ba o ara mi
Eje ka sora nitori ilu orun
Gbogbo iranse olorun o mo mbebe
Eyin woli ateyin baba wa
Eje ka pada leyin aye ese yi
Kamaba kabamo ni nilu orun
Oba to ba wo be won ki ilade lori mo
Eni ba dale awon yen kii dale
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe laafin
Yara eewo kan mbe laafin
Credits
Writer(s): Segun Balogun
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.