Ojo Ayo

Eni timofe denu adun aye mi ni
Eni timo fo fun timo gbafun ife mi ni
Ololufe mi timo yan gege bi ishan ara

Timo ba nbinu, timo ba nbinu
Timo ba nbinu tonbemi tinba sope rara
Eyin e kanlo bami wa ololufemi lo

Okan toti gbona atutu lalai b'omi si
Iwo nimofe pe koma se'toju mi ni
Modupe p'awon obi e gba, won o sope rara

Bose nsemi gan mio leso, Olohun shaloye
Ololufemi afiwo naa lotunye
Bi adanwo ni oro ife toladun bi oyin, t'aba ti renikeji tonfeni denu

Jerryson production
Moyan ifemi nibi totida
Mio kabamo pemose l'aya
Olohun loni kinpe e lojoyen o, modupe Olohun motun t'opeda

Moyan ifemi nibi totida
Mio kabamo pemose l'aya
Olohun loni kinpe e lojoyen o, modupe Olohun motun t'opeda

MashaAllah
Moyan ifemi nibi to tidun o
Mio kabamo pemose loko
Olohun loni kingba lati fe e o, modupe Olohun motun t'opeda

Moyan ifemi nibi to tidun o
Mio kabamo pemose loko
Olohun loni kingba lati fe e o, modupe Olohun motun topeda

Miio shife mo r'olooto momu
Mio shiyan mo fenikeji s'aya
Mo nigbagbo pewo sha layan funmi o, kajo mawa ni dojo ale ayami

Moyan ifemi nibi totida
Mio kabamo pemose l'aya
Olohun loni kinpe e lojoyen o, modupe Olohun motun t'opeda

Mio f'àlè soko mo r'olooto fisoko
Mio siyemeji kinto ba e lo mogba
Pewo gangan leni ti a yan momi o, taojo gbepo dojo ale okomi

Moyan ifemi nibi to tidun o
Mio kabamo pemose loko
Olohun loni kingba lati fe e o, modupe Olohun motun t'opeda

Oni o mani kolofin ojo ayo ni, igbeyawo alarinrin lawase loni o
T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe

Oni o mani kolofin ojo ayo ni, igbeyawo alarinrin lawase loni o
T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe

Sebi nigba ti e rirayin sebi enikan soso
Lokoko so fenikeji pe jekadi ife ara?
Iyawo lokoko sako oloun o gba o

Oko e oje ko sinmi otun gbiyanju o
Pomo totutu niwa lojo, sowa gbodo loni?
Yoruba ni koje ngbadun lobinrin ngbafun

Oun gangan niyawo e fiwa pada gba o
Toko tiyawo alarede ti d'oloruka o
E jeka fayo bawon dupe

Oni o mani kolofin ojo ayo ni
Igbeyawo alarinrin lawase loni o
T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe
Oko iyawo tiso funmi o l'oriyomi o
Monife iyawo mi denu o koja wasa o

O l'egbin nimo lefiwe boje t'ewa ni
O l'adàbà lale fiwe boje t'iwa ni
O lodabi oju lara tio gbodo fo

O lodabi aso lara tio gbodo ya ni
O loun maloje koun mo adun ife o
Loje koun fi sepinnu poun gbodo fe

Ni tako tabo alarede ba doloruka o
Toko tiyawo alarede ti d'oloruka adupe

Oni o mani kolofin ojo ayo ni
Igbeyawo alarinrin lawase loni o
T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe

Iyawo matiso boseri lara oun gangan
Iyawo matiso boseri lara oun
O loko timofe wumi modupe oni o
O leni bi okan mi o koja okunrin

Tenikan leri ta gboju wipoun o ri
Ajanaku koja kokoja ka laomo
Iduro e ni kaso ni abi t'ewa ni
Abi t'iwa t'okunrin fi nsike aya

O loun gan time ipinnnu poun gbodo fe
T'oko tiyawo alarede ba doloruka o, eje kafayo bawon mujo

Oni o mani kolofin ojo ayo ni
Igbeyawo alarinrin lawase loni o
T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe

MashaAllah
Olohun ti soyin papo kema pada ja
Olohun to seyin lokan niko fadunsi
Oba toseyin lolufe emi ikorira

Koni gbajoba ife yin allahumma amin
Koni koro titi laye ife adun bi oyin ni
K'ifedayo ke dolope keyin masepada dota

Oni o mani kolofin ojo ayo ni
Igbeyawo alarinrin lawase loni o
T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe

Yah robbi maje kiwon tuka o Allah
Toko tiyawo oloruka ti dikanna o

Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai

Maje kiwon tuka o Allah
Toko tiyawo oloruka ti dikanna o
Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai

Yah robbi maje kiwon tuka o Allah
Maje kiwon tuka o Allah
Toko tiyawo oloruka ti dikanna o

Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin ma delesinrin amin

Maje kiwon tuka o Allah
Toko tiyawo oloruka ti dikanna o
Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai

Yah robbi maje kiwon suffer o Allah
Mase fiya dan won wo lailai

Ilahi ma yawon lagan amin o
K'esu masiwon lona Allah
Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin ma doniranu amin

Maje kiwon tuka o Allah
Toko tiyawo oloruka ti dikanna o
Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai

Iyawo ojo oni o Allah
Iyawo ojo oni o Allah
Maje koso foko e po tan
Ibagbe ibasepo ola
Maje ko diso'nu eku Allah

Amumora toba lefa ironu o
Maje kiyen osele Amin
Biwon sewa bere aye tuntun o ife
K'igbeyawo alarinrin ma doniranu titi lai

Maje kiwon tuka o Allah
Toko tiyawo oloruka ti dikanna o
Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai

Olohun, agbara toko o malo fise
Agbara toko yio malo fise
Olohun mafi won oko e amin
Maje kogba alagbase oru

Oro toko o malo ba fun
Maje k'oko o d'otubante o
Ola tio fi kebi e ba nfun
Biwon sefe bere aye tuntun tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin ma delesinrin, koma doniranu lailai

Maje kiwon tuka o Allah
Toko tiyawo oloruka ti dikanna o
Biwon sewa bere aye tuntun o ife
Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai

Alubarika ibe mafi dunwa karowo na
Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o
Omo abiro abiye tako tabo

Alubarika ibe mafi dunwa karowo na
Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o
Omo abiro abiye tako tabo

Terin tayo lafi pade ta finyo
Isoro ibe mafi kanwa kama sunkun o
Ka bawon gbe'beji abiro takotabo

Alubarika ibe mafi dunwa karowo na
Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o
Omo abiro abiye tako tabo

Ki toko taya mapada gbera sepe
Ife tobere ni konmalo dojo ale won
Irepo lafe kosele titi lai

Alubarika ibe mafi dunwa karowo na
Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o, omo abiro abiye tako tabo

Iyawo ti roko gbamu o adupe o
O l'abelejayan kewabi joko si

Oko ti riyawo e dimu o adupe o
O l'abelejayan kewabi joko si

Gbogbo Eni towa akiyin emama seun
Ao firu e gba pelode idunnu

Baba oko nkinyin pema mase o
Ao firu e gba pelode idunnu

Mama oko nkiyin pema mase ee
Ao firu e gba pelode idunnu



Credits
Writer(s): Oriyomi Kehinde Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link