Kirakita

Jerryson production

MashaAllah
Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira

K'eda sise bi erin, je ije eliri
Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire

Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye

Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira

K'eda sise bi erin, je ije eliri
Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire

Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye

Mo koseri doju ami, mosi gbominira
Igba tao r'owo gba shop, oju rito o laye

Anforiro t'ifarada pe toba pe o boya
P'ori ton suffer apada wa d'ori olola

Olohun o dojutimi, o funmi lona miran

Ofise orin damilola, koma tun funmi lasan

O semi ni arisami t'aye nri tonfola ke
Kon to p'akoko tabikeji, won a 'oriyomi sha

Kìràkìtà mi lotunlosi oba oluwa, lofi demilade
Kìràkìtà mi lotunlosi, oba oluwa lofi demilde

Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira

K'eda sise bi erin, je ije eliri
Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire

Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye

Bee
Loju olowo oledabi, bi pawon logbon
Loju talika yio maro polowo je tete

Etò l'olohun fisoro yi k'aye le segbe

Gbogbo eni tonfori ro kosikosi o laye
Olohun a sina yio pada da loju emi won

Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira

K'eda sise bi erin, je ije eliri
Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire

Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye

Gateman to ns'olode ati wole olowo
Nigba tio i rise yen, ogbon kobosi londa

Nigba tobosi opada di gateman olowo
Ori b'olowo se nfayo je aye olola

O wa nsadua k'olohun soun naa lolowo

T'adua tonse bapada gba toba d'olola

Selomi ko nio pada ma sole olowo?
B'aye seri leriyen eto Olohun loje

Ise tenikan sowipe ko kamo to tesiwaju

Ope lomaje felomi toba rise yen gbamu

Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira

K'eda sise bi erin, je ije eliri
Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire

Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye

Aseda mafimi sile seun taye mi nfe
Kinma d'iwole kinto pada gba oore timo nwa

At'iwe timo tun rika, je nrola fi muwa
Kinma fogbon pelu idea mi gbaye inira

Oba je k'aye fise mi lomi, tola finde
K'atiga layemi madeti, maje kole nira

Imo atoye topeye wumi kin r'aye gbe
Isoro masomi d'ode nibi tobaye fogbon

Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira

K'eda sise bi erin, je ije eliri
Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire

Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye

Aoni damu kato lowo lowo
Ise kekere owo nla ni kabawon se
Ise kekere owo nla ni kabawon se

Katodeni tayenfe isenla lase
Katodeni tayenfe isenla lase

Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa
Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa

Gbogbo wa laojo lowolowo
Gbogbo wa laoma kolemole

Gbogbo wa laoma ni lari

Aoni damu kato lowo lowo
Ise kekere owo nla ni kabawon se
Ise kekere owo nla ni kabawon se

Katodeni tayenfe isenla lase
Katodeni tayenfe isenla lase

Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa
Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa

Agbara lola tonije maje ko dole
Maje kosaini maje ko toshi

Ike ti koranti bere kobanfun
Ola ti koranti bere kobanfun
Aponle to ntowo re làwã bangbe fun

Agbara lola tonije maje ko dole
Maje kosaini maje ko toshi

Ike ti koranti bere kobanfun
Ola ti koranti bere kobanfun
Aponle to ntowo re làwã bangbe fun

Hajji lateef olumegbon alakanni mi
Olanrewaju amuludun accra ghana

Olumegbon ntoju mi fun t'owo t'ola
On gbiyanju k'aye timowa rorun

Bose nfife hanmi malo nfowo momi
Amuludun gbogbo accra ni ghana

Ola ti koranti bere kobanfun
Aponle to ntowo re lawa, bangbe fun

Agbara lola tonije maje ko dole
Maje kosaini maje ko toshi

Ike ti koranti bere kobanfun
Ola ti koranti bere kobanfun
Aponle to ntowo re làwã bangbe fun

Olohun tunbo ke latifu bose ngbero
Koje kola e tunbo fe dori omo

Toripe lojumo nimo nsadua fun
At'adua topo eniyn nse fun

Tiru e balo pe mefa laye mi, dangote afe bami sore ni dandan

Olanrewaju akanni maje owo e lo
Kawa tanje ninu e le gbadun si

Ike ti koranti bere k'olohun fun
Ola ti koranti bere k'olohun fun
Aponle to ntowo re làwã bangbe fun

Agbara lola tonije maje ko dole
Maje kosaini maje ko toshi

Ike ti koranti bere kobanfun
Ola ti koranti bere kobanfun
Aponle to ntowo re làwã bangbe fun

Ha, olanrewaju da pupo
Aye ngba fun e

Oko mosunmola big hajjia, summaiyah
Oko abebi aliyah, queen of queens

Baba yetunde baba mariam
Baba olansile baba kolayemi, ese gan

Al'olumegbon da pupo, aye ngba fun e

Mofeyale rashidi amole jeje
Dandan ni kinyale rashidi amole jeje

Baba onile tuntun rashidi amole jeje
Ilenla to koyen o mani jona

Eyi to tiko tele o mani wo lai
Eyi to tunku tomako o mani nira

Ha, omotosho rashidi amole jeje
Meter meter lowomi oteyi mo moore

Olohun ma gba alafia ara amole
Olohun mafi towa lenu wo ko funwa tan
Amole o seni laàbò odidi ni

Jejelayegba oko basira, oko shukura
Oko fatima (alase jeje haulage ebudola)

Bami k'alhaji ibrahima ishola popoola

Oko anifa oko maria, baba afusa baba amira

Oni maf'amole towa lenu wo ko funwa tan
Amole o seni laàbò odidi ni

Bo l'olawale maso p'òleyan, yusufu omo olaegbe da o

Atiwa atise yusufu lo sunwon
Eniyan lomo olaegbe sha

Gbogbo iwa e malo temilorun
Baba ilyas baba zainab

Baba Khalid baba oni maleek
Olaegbe sore mawobe, o sore
Olawale jeni togbayi, o sore

Ha, toripe rere malo nf'ojo aye e se
Aye nroyin e yusufu, wipe oseniyan gan ni

Saraa lon fojo aye e se
Aye nroyin e lawale, wipe oseniyan gan ni

Eniyan toba nioma sore
Ojeya tete sun kuro, fawon ton dena oore

Eniyan tobani omale sore
Ojeya tete sun kuro, fawon ton dena oore

Yusufu o tun wani sore
Kotun wa gaba lori e, konireti ope mo

Olohun onije omale sore
Toriyen ma lola nwo, tiofile jola o tan

Ore oni gbowo e kodiiiiii bi o
Ore o ni gbowo e ko dibi
Tor'aniyan toma nlo, tonitoni ma lonmo

Mo l'onilenla moleniyan toga
Moleniyan toga

Abbey de don, abbey de don, onilenla

Prince abiodun nilu germany, onilelenla
Alhaji alafe qomarudeen, onilenla

Baba saida baba gbolahan, onilenla

O loke timo gbero lati fo, ma debe
Oun tobagba lama fun, ma debe
Ao kan nikoja aye wani, ma debe

Oloke tingbero lati fo
Maa debe

Moki saheed omo olayode
Olatunde oko ejire amina

Alase olateed olaoluwa, baba olamiposi jamal mi

Baba ayomide azeezah mi
Baba korede mi adigun

Mentioning the names of die hard fans
Fun publicity won ngbiyanju o

Hajji rashidi akanmu agba
Omo bakare akanmu agunwa

Alase gloryland daddy mi agunwa
Alhaji nurudeen rereloluwa
Do good adedunmoye mi

Adisa oko alhaja abiba, oko alhaja nasiro

Alase ademola oba estate
Ema ku itoju mi oriyomi

Alhaji riliwan cooler olori
Oloriodo leni timowi

Oloriodo ijora kingdom
Hajja rofia obadara mi

Ara99 tonje arike, mama shubomi alaniade
Artist manager mi oriyomi

Innocent ahmed ayesoro
Manager mi baba adulrahman

Baba basit baba aliyah mi
Moki ismaila adisa ade

Ayomide emir 1
Moki owolabi mi anisere

Lookman baba faoziyah
Baba aliameen baba awwal

Jerryson production to tatata
Pelu hajji qubar engineer mi, ese

O loke timo gbero lati fo, ma debe
Oun tobagba lama fun, ma debe
Ao kan nikoja aye wani, ma debe

Oloke tingbero lati fo
Maa debe



Credits
Writer(s): Oriyomi Kehinde Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link