Iranlowo (My Help)

emi o GBE oju Mi sori Oke wonni
nibo ni ranlowo Mi,
yio a ti wa AAA
Iranlowo Mi o todo oluwa wa
ti o da orun oun aye

Iranlowo Mi latodo re ni oba to da orun aye
ranmilowo oluwa, ranmilowo

oun ki yio je ki ese mi koye
eniti n pamimo kiitogbe beeni kii sun rara oo
e no de sleep huuuuuu

Iranlowo mi latodo re ni, oba to da orun aye, ranmilowo oluwa ranmilowo

ranmilowo 4x



Credits
Writer(s): Damilola & Bekes
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link