Ologun L' oluwa

ologun loluwa, gbani gbani ma fi ti bon se
baba alagbara to gba gbara lowo alagbara.
ogbeni nija keru o boni ja oba alade alafiaa.
gbogbo ilekun ayeraye
e gbori yin soke
gbogbo ilekun ailowolowo mo pase
e gbori yin soke
gbogbo ilekun aibimo
e gbori yin soke
gbogbo ilekun ailegbadura
e gbori yin soke
gbogbo ilekun aisefe olorun
e gbori yin soke
ko ba ogo le wole wa
oluwa to lagbara julo
asegun ati ajogun ni a je nipa eje kristi ani isegun boluwa be n fun wa a ki yoo subu ko so ogun to le bori agbara re
asegun niwa nipa eje jesu, baba fun wa nisegun nipa eje jesu eni ta pa felese sibe o wa o njoba awa ju asegun lo o o, awa ju asegun lo.

soro saye wa baba
soro saye wa baba
baba mimo ja fun mi o
ja ja ja fun mi o



Credits
Writer(s): Damilola & Bekes
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link