Afoju

To ba n rin l'okunkun
ko le mo, afoju ni
To ba n jeun eleera
Ko le mo, afoju ni
To ba r'omoge to rewa eeeh
Ko le mo rara
Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua

To ba n rin l'okunkun

To ba n rin l'okunkun ko le mo rara
Ko le mo, afoju ni afoju ni
To ba n jeun eleera eh
Ko le mo, afoju ni afoju ni bawo lo se fe mo
To ba r'omoge to rewa eh ah
Ko le mo rara agaga eeh
Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua

Oju L'obara o, okunkun o da
Eda mi gbo
Etewo adura araye, ka ma f'opa rin Amin o
Eniyan buru ninu aye won le pokun meko fun ni beeni aye buru
Aye mi d'owo re, ba mi so, mo mi n bebe o aye mi d'owo re o

To ba n rin l'okunkun ma je k'omo araye so mi
Ko le mo, afoju ni s'okunkun e
To ba n jeun eleera
Ko le mo, afoju ni
To ba r'omoge to rewaa eeeh
Ko le mo rara ko le mo rara
Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua ma so mi s'okunkun osan o

Gbogbo abarapa, e ranti abirun e ma ranti won
E ma se'ranlowo, ema di kun won l'eru rara
Ti won to won gbe, oro aye kanpa o
Ara aye e buru
To ba fe ni loju, won a tun f'ata s'enu Aye

To ba n rin l'okunkun
Ko le mo, afoju ni
Bawo lo se femo
To ba n jeun eleera
Ko le mo, afoju ni At'owuro, at'osan, at'ale
To ba r'omoge to rewa eh lo dudu l'oju afoju
Ko le mo rara ko le mo o
Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua Ma so mi s'okun ooh

Oju L'obara o, okunkun o da
Eda mi gbo eda mi gbo
Etewo adura araye, ka ma f'opa rin unh unh
Eniyan buru ninu aye won le pokun meko fun ni eh
Aye mi d'owo re, ba mi so, mo mi n bebe o ba mi so o Baba

To ba n rin l'okunkun To ba rin l'okunkun
Ko le mo, afoju ni Bawo lo se femo
To ba n jeun eleera To ba n jeun
Ko le mo, afoju ni To ba n jeun alayan
To ba r'omoge to rewa eh eeeh
Ko le mo rara ko le mo rara
okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua Ma so wa s'okun ooh

To ba n rin l'okunkun ah ah ah ah
Ko le mo, afoju ni Gbogbo abarapa
To ba n jeun eleera
Ko le mo, afoju ni E toju afoju yin
To ba r'omoge to rewa eh Mo nigbagbo pe
Ko le mo rara lojo ojo kan
Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua won a l'aju bi ti...



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link