Eyin Okunrin

Iwa yin le
Iwa yin le
Olorun lo le gba niyan
Olorun ko-ko obirin yo

Eyin te s'aya deru
Eyin te so'aya di inu le o
Eranti Eleduwa n woyin, e o gba ere
Laiye, kin se lorun nikan

Iwa yin le
Iwa yin le
Olorun lo le gba niyan
Olorun ko-ko obirin yo

Okurin oloju ran koko
Abe seku bi ojo egbo
Eyin s'ogun dogoji oni fe fawo raja
Ito to tan lenu alawi jare yin o

Iwa yin le
Iwa yin le
Olorun lo le gba niyan
Olorun ko-ko obirin yo

Oun da pani
Ofi ida beri obirin
Ti o le gba ko un da ko ja ni waju ile won
Olorun ko ko obirin yo

Iwa yin le
Iwa yin le
Olorun lo le gba niyan
Olorun ko-ko obirin yo
Iwa yin le
Iwa yin le
Olorun lo le gba niyan
Olorun ko-ko obirin yo



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link