Eso Lore Iwa

(Eso o), eso, eso o, eso lore iwa o
Eso o, eso o, eso lore iwa (egbo)
B'eso ba da ni layi si iwa ko pe eniyan o
Ile lati keso ro de omo tako ti o gba
Teso tiwa oun lo sonu eso lore iwo o (mejeji lo sonu o)
Eso, eso o, eso lore iwa o
Eso o, eso o, eso lore iwa (egbo)
B'eso ba da ni layi si iwa ko pe eniyan o
Ile lati keso ro de omo tako ti o gba
Teso tiwa oun lo sonu eso lore iwo o

Belegan ba tan e ma se gba omo mi gbo
Ko ri nu e ma ta ko to de wu wa rere

Eso, eso o, eso lore iwa o
Eso o, eso o, eso lore iwa
B'eso ba da ni layi si iwa ko pe eniyan o
Ile lati keso ro de omo tako ti o gba
Teso, tiwa oun lo sonu eso lore iwo o

Irinsini o sani lojo iwuwa sin i o so ro o
Ke ti ku ma ta ko o wu wa dada

Eso, eso o, eso lore iwa o
Eso o, eso o, eso lore iwa (egbo)
B'eso ba da ni layi si iwa ko gbe eyan o
Ile lati keso ro de omo tako ti o gba
Teso tiwa oun lo sonu eso lore iwo o

Belegan ba tan e ma se gba omo mi gbo
Ko ri nu e ma ta ko to de wu wa rere

Eso, eso o, eso lore iwa o
Eso o, eso o, eso, lore iwa
B'eso ba da ni layi si iwa ko gbe eyan
Ile lati keso ro de omo tako ti o gba
Teso, tiwa oun lo sonu eso lore iwo o
Eso, eso o, eso lore iwa o
Eso o, eso, eso lore iwa (beeni)
B'eso ba da ni layi si iwa ko gbe eyan o
Ile lati keso ro de omo tako ti o gba
Teso, tiwa oun lo sonu eso lore iwo o



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link