Mase Mase
Mase-mase, mase-mase kin gbo o
Afi to ba te
Mada-mada, mada-mada kin gba o
Eje ko kan di ninu iyo
Baja ba fori ko'mi, igba yen lo ma mo ona ile olowo re
Ewi fun igba un bo o, e pariwo o tan-tan, tan-tan ko ma ni pe mo
Ti gbogbo mo dara, to fara so fo a kowo boju ti o ni ri omi

Ti gbogbo mo dara to fara so fo, a kowo boju ti o ni ri omi
Mase-mase, mase-mase ya lo ja wo o omoge iwoyi
Mada-mada, mada-mada e jowo e gba tori ojo ola yin
Alagbeda asiki won be nigboro ilu tan jale

Ti gbogbo mo dara to fara so fo a kowo boju ti o ni ri omi

Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
- Ayemi Ayemi
- So Irin Mi
- Elenini Amutorunwa
- Afoju
- Mowowa Aye
- Asiri Bibo
- Omo Laso
- Eyin Okunrin
- Eso Lore Iwa
- Mase Mase
All Album Tracks: From the Archive of Tope Alabi: Sound Track Compilation (Version 1) >
Altri album
- God's Servant at 70
- Unfading Covenant of Baba Abiye, Ede at 80 (feat. Chigozie Wisdom, Lekan Amos, Bukola Bekes, Elijah Akintunde, Prophet Timothy Funso Akande & Prophet Samson Oladeji Akande) - EP
- The Unusual Praise (Live)
- Oluwa Ni: The Spontaneous Worship
- Best of Tope Alabi
- Hymnal vol.1
- Mori Iyanu
- Igbowo Eda
- Funmilayo
- Unless You Bless Me
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.