Omo rere

Se pe mo le domoore laarin awon omo gidi
Se pe mo le domo gidi laarin awon omo rere
Se pe mo le domore laarin awon omo gidi
Se pe mo le domo gidi laarin awon omo gidi
Emi to gbero lojosi ka ta soja fi reja
Se pe mo le domo re laarin awon omo gidi
Se pe mo le domoore laarin awon omo gidi
Se pe mo le domo gidi laarin awon omo rere
Se pe mo le domore laarin awon omo gidi
Se pe mo le domo gidi laarin awon omo gidi
Emi to gbero lojosi ka ta soja fi reja
Se pe mo le doba omo laarin awon omo gidi

Opo sorosoro wa lori afefe laye ti yeye lojosi
Pe ko le foro jeun
Opo sorosoro wa to ti lamilaka laye ti yeye ri
Wipe ko le foro jeun
Won ni ogbeni awoko jowo gbejo e si bi kan
Eni to pada le lojosi deni won pada fe wari fun

Se pe mo le domoore laarin awon omo gidi
Se pe mo le domo gidi laarin awon omo rere
Se pe mo le domore laarin awon omo gidi
Se pe mo le dolu omo laarin awon omo gidi
Emi to gbero lojosi ka ta soja fi reja
Se pe mo le domo re laarin awon omo rere

Opo osere osere lori itage o taye ti yeye ri wipe
Alaigboran ni Opo osere osere lori itage wa
Taye ti yeye ri wipe alaigboran ni to ba lo je obirin
Won a ni oniranu ni to ba lo jokunrin
Won a ni alagbere ni ko sunle ko sunta ko de tun ri
Kobo mu wale sugbon nigbeyin gbeyin won a di
Gbajumo taye n fe celebrity eni nla

Se pe mo le domoore laarin awon omo gidi
Se pe mo le domo gidi laarin awon omo rere
Se pe mo le domore laarin awon omo gidi
Se pe mo le dolu omo laarin awon omo rere
Emi to gbero lojosi ka ta soja fi reja

Credits
Writer(s): Evang Friday
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link