Opo eda

Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won
Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won

Omo a fise wo
Soun lo n dagba
Omo a fise wo
Soun lo n dagba
Opo omo a foju ojo bi
Mo ni won o da nkan
Owon omo to lo soke
Lai se pe won jeya
Eni o fara sise o yoo fara jise o

Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won

Fara dawosi eni
Ko ma degbin bo dola
Fara dawosi eni
Ko ma degbin bo dola
Akitan ti ko gbegbin
Won ti ni ko ki i kun boro
Won ni ko kose
O niwo ni kose o ti gbagbe pe
Eni ti o se bi alaaru loyigbo
Ko ni le se bi adegboro loja oba
Won ni o kawe o so poun o ka
Firun dudu sise ko ma baa
Firun funfun gbegbaaru lojo aye re

Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won

Ma se gbagbe o eni maa farayola
A koko fara yegbin
Jiya die loni o
Ma se gbagbe eni maa farayola
A koko fara yegbin
Jiya die loni o
Iya ti o je loni yoo doro
Bo dola kewura to di podan o
O ti ko lana koja
Atipe oun ta o ba jiya fun
Ko ni le tojo oun a ba sise fun
Lo n pada pe lowo eni o

Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won

Ikoko tiii yoo jata idi re
A koko gbona
Omode yi o jiya o so poun
Gbon o e jewo e bi
Ta wa ni tisa won
Sebi tita riro la n kola laye
Igba to ba jina lo n pada wa doge
Bonila o ba kolola mo
Itan polola lo kola fun sebi yen
Ko ni pare
Oga o ni sai sise oga
Omose ni ko hunble o
Nitori ola won

Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won

Omi adagun abeeri loju
Omi to n san yen o
Oun lo mo kanga
Eda to nibi re ti o
Lo n fosi lese
O da mi loju yoo pada ri
To ba ya
Ma koja mi olugbala
Ki i sorin a kunle ko o
Dakun jowo o tete ya mulele

Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won

Iwo ti sise ore mi o
O ti lowo lowo
Dakun jowo o ma
Se laulau ni tire
Boba joni lowo
O ye ka fi jole
Oun to koju seni kan
Eyin lo ko selomiran se o
Ilu gangan soun sa ni oro yi o
Eyi ta gbe kapa araye n jilu
Anbelentase eyi ta gbe siyara o

Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won
Opo eda n jeya lai le koya
Tori poti koya nigbati ko ye
Igba toye ki won jiya
Soun ni won ti koya
Iya wa n fiya joniya won



Credits
Writer(s): Evang Friday
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link