Ojo ale

Eru ojo ale n ba mi
Tori n mo bi yoo ti ri
Eru ojo ale n ba mi o o
Tori n mo ibi oloko
N wa mi lo
O n ba mi o
Eru ojo ale n ba mi
Tori n mo bi yoo ti ri
Eru ojo ale n ba mi oo
Tori n mo bi oloko
N wa mi lo

Opo arugbo ni mo ri
Lojo ale ti won fo loju o
To n mu won rin kiri
Ko ma ki se pe
Won ko le gbadura
Ibi tile su bawon
Sowun lo wa yen
Opo arugbo ni mo ri lojo ale
Tiwon toro je ti won n mu won
To kiri ki ma i se pe won ko
Lolorun o ibi tile su ba won
So hun lo wa yen

Eru ojo ale n ba mi
Tori n mo bi yoo ti ri
Eru ojo ale n ba mi o o
Tori n mo ibi oloko
N wa mi lo
O n ba mi o
Eru ojo ale n ba mi
Tori n mo bi yoo ti ri
Eru ojo ale n ba mi oo
Tori n mo bi oloko
N wa mi lo

Opo arugbo ni mori
Lojo ale ti won ti sise
Latowuro won
Sugbon ti won o ri ohun
Kojo o
Ki ma i se pe o
Tori won yole
Opo arugbo ni mo ri lojo ale
Ti won n jeya bi enipe
Won o bimo saye
Ko ma i se pe nitori
Won o bimo o
Sugbon aye lo ko
Lo ko eyin omo si won
Opo sise sise bi alai se
Ko ma si n ti won le toka si
Ko ma i se pe won yole o
Ibi tile su bawon
Sohun lo wa yen

Eru ojo ale n ba mi
Tori n mo bi yoo ti ri
Eru ojo ale n ba mi o o
Tori n mo ibi oloko
N wa mi lo
O n ba mi o
Eru ojo ale n ba mi
Tori n mo bi yoo ti ri
Eru ojo ale n ba mi oo
Tori n mo bi oloko
N wa mi lo

Won ni o ye sebi
O lo ni gbo
Won o ye seka
O lo ni gba o
Ojo aye re n yo lo
Bi abela o je ronu aye re
Ki wo tete se rere
E o wo oju ojo
Se wo o wo oju agogo
E o wo ohun ago wi
Se wo o wo oju ago ni
Igba eda n re bi ano
Ojo oni n ba ti e lo
Ohun iseju kan baje
Ogun odun le ma tun se
Agbere lo se titi to sogo nu
Oti lo mu titi ojo aye re lo
Agogo to ka wakati o duro o
Ronu re wo ko ma bola re je
Ika lo se to fi pa omo inu re tan
Sika sika yin o wa fi kan sera re
Gbogbo omo to bi o ri pe
Won o ni laari
Ronu e wo nitori ojo ola

E o wo oju ojo
Se wo o wo oju agogo
E o wo ohun ago wi
Se wo o wo oju ago ni
Igba eda n re bi ano
Ojo oni n ba ti e lo
Ohun iseju kan baje
Ogun odun le ma tun se

Kojo ola mi le dara o
Mo to o wa olorun
Ba mi tunse
Kojo ola mi le dara o
Mo to o wa olorun
Ba mi tunse
Mi o lebu ajitola
Mi logun ajisa
Mo to o wa olorun o
Ba mi tunse
Ki n le lojo ale baba
Ki n ma ba rare o jare
Mo to o wa olorun
Ba mi tunse
Mo to o wa o
Mo to o wa olorun
Ba mi tunse



Credits
Writer(s): Evang Friday
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link