Iyin ogo

Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba ai ku o
To fimole bora bi aso o
Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba aiku o
To fimole bora bi aso o

Ninu aye ko soba bi re
Olori aye olola nla
Eleru iyin to sole aye ro
Kinihun juda mo n seba re
Mo wari foba o

Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba ai ku o
To fimole bora bi aso o
Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba aiku o
To fimole bora bi aso o

Ologbo aye n gbon fun baba
Ogbon to nile ogbon eh
Ologbo aye gbon fun baba
Ogba to nile ogbon
Ogbon taye gbon ko to gbon
Bata baba onile ogbon
Ologbon aye n dobale fun baba
To dori ogbon o

Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba ai ku o
To fimole bora bi aso o
Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba aiku o
To fimole bora bi aso o

Mo gbon titi wole alagbon
Ko ya mi logbon
Mo gbon titi wole alagbon
Ko ya mi logbon
Ba ologbon ni ki n ma gbon
Ki n jugbon fagbon
Mo jugbon fagbon
Agbon lo jale
O tule agbon ka
Ologbon aye o gbon tele
Ogbon ni won da

Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba ai ku o
To fimole bora bi aso o
Iyin ogo ye ja jehovah
Olori aye oba aiku o
To fimole bora bi aso o

Okiki re ni n o maa ke oluwa
Okiki re ni n o maa ke
Okiki re ni o ma ke o
Okiki re ni n o ma kee
Nile yii loke okun ati
Ni gbogbo agbaye
Okiki re ni n o ma ke
Ojo ti ojo n foun o mu
Ogo re jade
Okiki re ni n o ma ke
Orun de orun ti ran
Ni gbogbo agbaye ni o
Okiki re ni n o maa ke
O fun mi lalafia
Mo n jegbadun ara mi e seun
Okiki re ni n o maa ke
Oju mi o fo bee eti mi o di
Okiki re ni n o maa ke
Mi o bo sowo ajinigbe
N bo sowo ajini pa
Okiki re ni n o maa ke
Ani wipe okiki re ni n o ma ke
Okiki re ni n o maa ke
Okiki re ni n o maa ke oluwa
Okiki re ni n o ma ke
Ojo ji ojo n fohun fimo re han o
Okiki re ni n o maa ke

A ni e ga ju angeli lo olorun mi
E ga ju angeli lo olorun mi
E da won oke tenikeni o ga to
E da won angeli to ga ju awon oke lo
E ga ju angeli lo olorun mi baba
E ga ju angeli lo olorun mi
E ga ju angeli lo olorun mi
E da won oke tenikeni o ga to
E da won angeli to ga ju awon oke lo
E ga ju angeli lo olorun mi baba
E ga ju angeli lo olorun mi
Salm 93 mo ra won oro kan
Oluwa joba ola n la le wo laso o
Agbara ni oluwa mi wo laso o
O fi di ara re ni amure o
Ohun owo mi o to n o fi gongo fa
Oro omo araye soun sa niyen
A ni ki lowo olorun o to jare o
O ga ju angeli lo olorun mi

A ni e ga ju angeli lo olorun mi
E ga ju angeli lo olorun mi
E da won oke tenikeni o ga to
E da won angeli to ga ju awon oke lo
E ga ju angeli lo olorun mi baba
E ga ju angeli lo olorun mi

Tani ki n gbega tani ki n gbe
Igbati n ba yin olorun o
Ta ni ki n gbega
Tani ki n gbe ga ta ni ki n gbega
Igbati n ba yin olorun o tani ki n gbega

Man made god a powerless god
I say man made god a powerless god
I will never worship man made god
Tani ki n gbega tani ki n gbe
Igbati n ba yin olorun o
Ta ni ki n gbega
Tani ki n gbe ga ta ni ki n gbega
Igbati n ba yin olorun o tani ki n gbega

Iyin ola ogo ni fun o
Agbara tipe je ti ire
Egberun ahon ko to yin o
A wa wole a juba re

Tani ki n gbega tani ki n gbe
Igbati n ba yin olorun o
Ta ni ki n gbega
Tani ki n gbe ga ta ni ki n gbega
Igbati n ba yin olorun o tani ki n gbega

Mimo mimo mimo nimole
Imole kristi to sokale
Sori ayanfe gbogbo awon
To gbaa imole yii gbo yoo ri iye
Iye ayeraye

Tani ki n gbega tani ki n gbe
Igbati n ba yin olorun o
Ta ni ki n gbega
Tani ki n gbe ga ta ni ki n gbega
Igbati n ba yin olorun o tani ki n gbega

Ipin nla ti jesu file le leyi oo
Baba aladua ko
Keda ma se ro pe mo duro nile
Mo duro lori kriti apata
Kerubu eyo
Kerubu eyo serafu eyo
A ti fipin re lele ni otito
A ti fi pin re le pelu ododo

Igba ti n ba yin olorun o
Ta ni ki n gbe ga
Tani ki n gbega tani ki n gbe
Igbati n ba yin olorun o
Ta ni ki n gbega
Tani ki n gbe ga ta ni ki n gbega
Igbati n ba yin olorun o tani ki n gbega

Baba n ma fiyin mi fun
Baba n ma fiyin mi fun o
Baba n ma fiyin mi fun
Baba n ma fiyin mi fun o
losan ati loru
Baba n ma fiyin mi fun o
Lojo gbogbo nigba gbogbo
Baba n ma fiyin mi fun o
Ni gbogbo igba gbogbo asiko
Baba n ma fi yin mi fun o
A ni baba n ma fiyin mi fun
Baba n ma fiyin mi fun o
Nile yi ni loke okun o
Baba n ma fiyin mi fun o
Nile yi ni loke okun
Baba n ma fiyin mi fun o
Lojo gbogbo ni gbogbo asiko
Baba n ma fiyin mi fun o
Nigbati ojo mi o fo
Baba n ma fiyin mi fun o
Koda nigba teti mi o di o
Baba n ma fiyin mi fun o
Tile mi n be lalafia
Baba nma fiyin mi fun o
Olorun orun lo ke mi se
Baba n ma fiyin mi fun o
Baba n ma fiyin mi fun
Baba n ma fiyin mi fun o

Emimo gbayin atogo
latenu mi o emimimo
Gbayin atogo
Gbayin atogo
Emimo gbayin atogo
Gbayin atogo emimimo
Gbayin atogo latenu mi
Emimo gbayin atogo
Latenu mi o emimimo
Gbayin atogo
Gbayin atogo
Emimo gbayin atogo
Gbayin atogo emimimo
Gbayin atogo latenu mi
Olori aye gbayin atogo
Latenu mi o emimimo
Gbayin atogo
Gbayin atogo
Emimo gbayin atogo
Gbayin atogo emimimo
Gbayin atogo latenu mi

Ko le jasasan e le ja sa san
Ko le jasasan e le ja sa san
Iyin ope osan atoru e le ja sasan
Ko le ja sasan e le ja sasan
Ko le ja sasan e le ja sasan
Ko le ja sasan e le ja so fo
Ko le ja sasan e le ja so fo
Awe pelu adura mi e le ja sasan
Ko le ja sasan e le ja sasan
Ko le ja sasan e le ja sasan
Iyin ope osan atoru e le ja sasan

Oluranlowo ayanmo
Oluran lowo kadara
Oluranlowo ayanmo o
E wa mikan ke gbe mi dide
Oluranlowo ayanmo
Oluranlowo kadara
Oluranlowo ayanmo
E wa mikan ke gbe mi dide

Okiki dara toro ma n wun yan
Sugbon owo gangan sa ni master fun
Okiki atowo o sowun lo wemi o
Olorun jowo gba dura mi o

Oluranlowo ayanmo
Oluran lowo kadara
Oluranlowo ayanmo o
E wa mikan ke gbe mi dide
Oluranlowo ayanmo
Oluranlowo kadara
Oluranlowo ayanmo
E wa mikan ke gbe mi dide

Tori mo ti kuro leyin
Mo ti kuro leyin
Mo ti kuro leyin se o
Mo ti kuro leyin
Mo ti kuro leyin
Mo ti kuro leyin
Koda iwaju ni mo wa
Mo ti kuro leyi o
Ha iwaju mo wa se o
Mo ti kuro leyin o
Number one ni mo wa
Mo ti kuro leyin o
Mi o de to seyin anybody se o
Mo ti kuro leyin o
Oke salaye wa
Mo ti kuro leyin o
Oke salaye wa se
Mo ti kuro leyin o
Ko ounje nbe loke
Mo ti kuro leyin
Ounje n be loke gan
Mo ti kuro leyin
Emi ti kuro ni lacal
Mo ti kuro leyin
Mo ti kuro lacal se o
Mo ti kuro leyin o
International mo wa
Mo ti kuro leyin
International mo wa o
Mo ti kuro leyin

Olorun somi dogo agbaye o
Baba somi dogo agbaye o
Baba ogo agbaye o
Baba somi dogo agbaye o baba
Baba somi dogo agbaye o baba
Ki n ma taku sogo eko nikan
Baba so mi dogo agabaye o baba
Ki ma taku sogo naija nikan
Baba somi dogo agbaye o baba
Omo america lo wun mi o
Baba somi dogo agbaye o baba

Ilu oba pemi mo fe lo yin baba
Mo n lose lati lo korin iyin
Mo n lo se lati yin baba
Ilu alawo funfun pe mi ki n wa
Gboruko olorun ga
Mo n lo se o la ti lo korin iyin
Mo n lo se lati yin baba
E ma se ka mi mawon olodo omo
E ma se ka mi mawon olodo omo
Olodo eniyan sa ni failure o
E ma se ka mi ma won olodo
E ma se ka mi mawon olodo
E ma se ka mi mawon olodo
Olodo eniyan sa ni failure o
E ma se ka mi ma won olodo
Awon kan ti ro pe n o sagbe jeun
Dady awon kan ti ro po ye ki n toro ni
Alasepe pada mu mi bo gbogbo won o
A ni awon ti ro pe mo fe wa sagbe ni
E ma se ka mi mawon olodo
Olodo eniyan sa ni failure o
E ma se kami ma won olodo
Orere mo wa to ti ri mi
Orere mo wa to ti ri mi
Won loun lo n bo yen
O ma to toro
Won loun lo n bo yen
O ma wa sagbe ni
Won a loun bo yen
O ma to toro
Igbati mo de be
Mo fun won lounje je o
Agbado ah di won lenu
E ma se ka mi ma won olodo
E ma se ka mi ma won olodo
Olodo eniyan sa ni failure o
E ma se ka me ma won olodo

Eru oba ba mi o
Eru oba ba mi o
Arobafin a pa da te o
Eru oba bami o eh
Eru oba ba ba
Ba ba bami o oo
Ayeraye o kabiesi
Olodumare gbengbele
Iku ti n wole iku o
Ah eru oba ba ba ba
Eru oba bami o
Arobafin a pada te o
Eru oba bami o eh
Arobafin a pada te o
Eru oba bami o eh
Arobafin a pada te o
Eru oba bami o eh
Arobafin arobafin loba
N pa mo sumoba niwon
Egbeje mo jina soba niwon
Egbefa arobafin a pada te o
Eru oba ba mi o eh

Agbada ola re da no o
Rora ma jo solorun orun
Oba re ah
Agbada agbada agbada
Agbada dady agbada ola re da na o
Rora ma jo solorun orun
Oba re ko gbosuba feledumare
Rora ma jo solorun orun
Oba re weriweri omodakedake
Baba agba
Rora ma jo solorun orun
Oba re



Credits
Writer(s): Evang Friday
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link