Mo Se Ba

Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun t'oni ikawo ohun gbogbo
Emi juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo

Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo

Eniyan meji nbi omo kan soso
Okan soso na a ma la won l'ogun gidi
Obi le bimo meji k'enu won ma ka won rara
Iwo mighty olorun ti ipa re ka gbogbo aye
(Iwo lo tobe)

Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo

Won f'eniyan je Baale t'enu re o ka baa
Oba n je lori ilu ti ilu o de tori e toro
Ginigini ti wu a re wo ti ko r'oju ara re
Aye o'niyan orun n wa riri ni oruko re

Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo

Iwo l'olorun
Iwo l'oluwa
Iwo l'olorun to pe ohun gbogbo wa
Oro to lase lori ohun gbogbo to da o pata
Eni ti o le mu ko si ninu ise owo re
O lagbara lori eda patapata

Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo

Mo se ba f'olorun agbaye
Mo se ba f'olorun t'oni ikawo ohun gbogbo
Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo
To lagbara lo'ori eda gbogbo

Mo se ba oluda nibo lo o le yi aye si
Talo to o
Talo ju o
To ba pase f'ojo ko yi pada
Kabiesi tani o bi oo
Olorun eran ara
Agbara re lo s'edidi ohun gbogbo
Iwo to s'oku di iye
Eleri idi
Sababi orun to gbe aye duro wawa

Olodumare
Oye k'eda gbogbo beru re
Olorun ogo
Oye k'eda gbogbo beru re

Iwo to ni eemi ati emi inu
Ipinlese aye orun wa ni kawo re
Baba oo
Oye k'eda gbogbo beru re

Olodumare
Oye k'eda ma wa riri fun
Alagbara giga
Oye k'eda ma wa riri fun

Iwo to le pa to le ji
Ototan
Sikun aye sikun orun
Ta lo le gba lowo re
Aaah
Oye k'eda ma wa riri fun

Olodumare
Oye k'eda gbogbo beru re
Awimayewun alagbara ju lo
Oye k'eda gbogbo beru re

Iwo to ni eemi ati emi inu
Ipinlese aye orun wa ni kawo re
Alagbara oo
Oye k'eda gbogbo beru re

Olodumare
Oye k'eda ma wa riri fun
Onise iyanu
Oye k'eda ma wa riri fun

Iwo to le pa to le ji
Ototan
Sikun ogbon sikun apadi
Nbe lowo re
Baba ooo
Oye k'eda ma wa riri fun

Iba re o Olodumare
Ogo ma ni fun oo



Credits
Writer(s): Tope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link