Toju Inu E

Ohun ti ẹda ma je laye, inu e lo wa
Ibi ti ẹda ma de laye, inu e ẹ lo wa (oh oh oh)
Ẹda o le mu ona oko kan,ko gbe lagodo dani
Ero to lo sodo nikan ni yo pọn omi bo wa'le

Toju inu e
Toju inu e
Toju inu e oh
Toju ero re oh

Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo, ke gbo o ke gba
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ ati ero re
Tori ohun to ba n ro(toju inu rẹ)
Ohun na ni yo je jade(toju inu rẹ)
Ninu Irinajo aye rẹ (toju inu rẹ)
Oh oh oh oh (ati ero re)
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo, ke gbo o ke gba
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ ati ero re

Akaba ti ẹda ma gun l'aiye inu rẹ lero wa
Ẹda ti o wo aso alárè inu e a dan
Alai niran ti o n ki oba ninaro, ko le jọ yẹ laye laye
Tori eni to ba mo iwura, la mi ta a fun

Ero rere lo n gbe ni de bi giga (toju inu rẹ)
Bẹẹni mo wí (toju inu rẹ)
Ko ya toju inu rẹ (toju inu rẹ)
To kan rẹ ba todi ko ya fo (ati ero re)
Isesi e larin ero
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo, ke gbo o ke gba
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re
Toju inu rẹ (toju re)
Toju inu rẹ (guide your heart with all diligence)
Toju inu rẹ (bẹẹni mo wí se)
Ati ero re (tori e ibẹ ni gbogbo ohun ti a fe je laye wa)
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo, ke gbo o ke gba
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ ati ero re (toju re daada, se dada)

Awujo awon to n ba rin
Awa o lati inu ẹ
Eyan meji o le rin papo
La Lai sepe won mo owo ara won
Obun ti o fi omi osu kan kanra
To wa pa la gan na ni were
Oye ko mo pe ologiri omo ekun ni
Eni to n gbọn

Toju inu rẹ (to wa pade e ni ma lulu)
Toju inu rẹ (abi é rí pe oro ti bu se)
Toju inu rẹ (bẹẹni mo wí se)
Ati ọkan rẹ (oje ya tọju inu rẹ)
Ero gbogbo (tori oje ki lo fere)
Ero gbogbo (awọn kon se ore arire ma bọ)
Ero gbogbo
Ero gbogbo, ke gbo o ke gba
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re

Ero ti ẹda ro laye lo n gbe won rin irin ajo otọ tó
Bi ọkan eda ba buru laye, aiye rẹ a sha mala mala
Agborin rin irin ẹwà bo lọnà, ijapa wa koto sọnà fún
Se ere taja fi ogun odun sa ni fa n ga lesin fin Yan
Koto ti ijapa wa sile naa ni o ni je ko lo
Odun ti Kinihun ti pa era je se laja se ayan
Ma sọ o ero okan re
Be positive all the time bo ti wun ko ri
Ero inú do ri ayanmọ kodo ke ya sọ
Opo ohun ti ẹda ro, o bawon rin irin ajo
Eni ro rere, o si ṣe é
Eyan to ro ika o sí se
Opo ohun ti a ri laye eda ero won ni
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re

Toju inu rẹ
Toju inu rẹ
Toju inu rẹ
Toju ero re
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo, ke gbo o ke gba
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re
Toju inu rẹ
Toju inu rẹ
Toju inu rẹ
Ati ero re
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo
Ero gbogbo ke gbo o ke gba
Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re
Toju inu rẹ toju ọkan rẹ pẹlu ero re
Toju inu rẹ toju ọkan rẹ pẹlu ero re



Credits
Writer(s): Tope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link