Otami

(It's Protunez on the beat)

Ẹbilà, ẹbilà
Ẹ yàgò, ẹ yàgò
Ọmọ olóore tí dé, ká lọ

Ìya to jẹ mí o, o gbọdọ jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọdọ tá mí gbé
Ìya to jẹ mí o, o gbọdọ jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọdọ tá mí gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Aṣa ń pekéde bí pé ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ nisẹ lo ń pi-rọrọ

Wọn ní p'oto o, má lo'to
Wọn ní k'òtò o, má bá wọn bùsi
Mo tí sọ fún wọn tẹlẹ-tẹlẹ pé ẹhìnkulé láṣẹ ní ń gbé
Inú'lé tẹrí yẹn, lẹni tí o ń ṣe ẹ wa-aah
O fẹ pẹ láyé, ojú ẹ o ní rí, ńkan ló máa f'ọwọ mù
Wọn ṣe ẹ rí, o lo make e
Wọn gùn ẹ rí, o lo lókígbe
Wọn yìn ìbọn fún ẹ rí, o lo layetà
Ìwọ má dírá, o tẹ tàn nìyẹn, my brother, ah

Ìya to jẹ mí o, o gbọdọ jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọdọ tá mí gbé
Ìya to jẹ mí o, o gbọdọ jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọdọ tá mí gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde (ń dé)
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Aṣa ń pekéde bí pé ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ niṣe lo ń pi-rọrọ

Gbogbo òun tójú rí kọ lẹnu máa sọ, ọrọ níí
Yára láti gbọ'rọ, lọ'ra láti f'èsì, ọrẹ míì
Wọn fí ẹ ṣọ mí, ọrẹ, jọ, má di monitor
Ò lọ school, jọ, ò kí ńṣe àgùnbanirọ
Nígbà tójú pọn mí, ọrẹ, o mọ pé ó jìnà sí mì gan-
Àwa náà ré, àti gòkè àti sọọ
Àje Ogungun-nisọ otí bá mí tàn
Ìgbà kàn rí nígbà yẹn, àwa ní janitor
Nísìnyí, ẹni f'ojú àná w'òkú, ẹbọrá áàbolaṣọ-uh-uh

Ìya to jẹ mí o, o gbọdọ jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọdọ tá mí gbé
Ìya to jẹ mí o, o gbọdọ jẹ mí gbé
Òṣì to tá mí o, o gbọdọ tá mí gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Aṣa ń pekéde bí pé ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ nisẹ lo ń pi-rọrọ



Credits
Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link