Gbare Gbare

Ah-wa-wa-wa, wa-wa, wa, wa, wa
Gbare (music)
Wa-wa-wa, wa-wa, wa, wa, wa
Áà gbàre

Gbàre-gbàre, ko lé gbàre ọjọ gbogbo
Ko má gbà bí ọjọ nkan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, má gbàre ọjọ gbogbo
Bò kú ọjọ kàn ibí, ọnà àlá, ọnà àláa

'Ṣẹdá mí, èya, sọrọ, 'ṣẹdá mí, eya, sọrọ
'Ṣẹdá mí, èya, dìde, 'ṣẹdá mí, eya, dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
Mù mí débẹ, mù mí débẹ, ah, kò tó pẹ

Ẹyẹlé mí rugbada re bi òkú, ah
Ẹyẹlé mí rugbada, ah
Ẹyẹlé mí rugbada re bi ọsa
Ẹyẹlé mí rugbada, ah-wa
Tótún, tòsí l'ẹyẹlé mí fí ko ore ajé wọlé
Oh-oh, rugbada, eh
Irè ajé kọ wọlé mí, kótún jáde mọ, mo rugbada
Olẹlẹ tó wọnú ẹkọ, o tún jáde mọ
Ẹ má pe rugbada

Gbàre-gbàre ko lé gbàre ọjọ gbogbo
Ko má gbà 'bí ọjọn kan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, má gbàre ọjọ gbogbo
Bò kú ọjọ kàn ibí, ọnà àlá, ọnà àláa

'Ṣẹdá mí, èya, sọrọ, 'ṣẹdá mí, eya, sọrọ
'Ṣẹdá mí, èya, dìde, 'ṣẹdá mí, eya, dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ (a-wa, wa-wa)
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
Mù mí débẹ, mù mí débẹ (milẹ), ahh, kò tó pẹ

Mo ṣetàn, mo dìde lá tí wá gbàre te mí
Ọlọrun míì
Olúbùnkún, olóore te mí, ẹ má kọjá mí Olùgbàlà, ah, ha
Irè iwájú, irè ẹhìn, irè òkè, irè ilẹ
Irè òtún, irè ósì, ko má jẹ tèmí Adegbọla, ọmọ Akande
Ore to wá ṣe yí Ọlọ́run, jẹ ko bá wá kalẹ
K'ọtá má ṣe rí wá poṣe

Gbàre-gbàre, ko lé gbàre ọjọ gbogbo
Ko má gbà 'bí ojo nkan rẹ o, oh-oh-oh-oh-oh
Èmi à gbàre, má gbàre ọjọ gbogbo
Bò kú ọjọ kàn ibí, ọnà àlá, ọnà àláa

'Ṣẹdá mí, èya, sọrọ, 'ṣẹ̀dá mí, èya, sọrọ
'Ṣẹdá mí, èya, dìde, 'ṣẹdá mí, èya, dìde
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ
Gbé wọn débẹ, gbé wọn débẹ o
Mù mí débẹ, mù mí débẹ, ahh, kò tó pẹ

(I am Izzyz productions)
Ẹyẹlé mí rugbada re bi òkú, ah
Ẹyẹlé mí rugbada



Credits
Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link