Aranbada

O'wu f'akuko, baba mi
Aranbada laye
Aranbada laye

Akuko baba mi kan lai lai
Owo ni o je, koni je agbado, oh-ohh
Akuko baba mi kan lai lai
Owo ni o je, koni je agbado, oh-ohh
Aranbada laye
Owo nio je oh, owo ni o je oh, oh-ohh
Ara n ba f'owo da
Owo nio je oh, owo ni o je oh

Money na the root of all evil
Ko de shey ma ni, tori owo yi dun
Kudiratulai, obirin lowo
Eyin obirin, e dakun, shet'emi
Owo, a pe ka'nuko
Owo, owo ihoho
That Gucci, Prada (owo ni)
Holiday for Bahamas (owo ni)
Gb'omo wa ki mi, owo lon na ni (owo lon na ni)

Akuko baba mi kan lai lai
Owo ni o je, koni je agbado, oh-ohh
Akuko baba mi kan lai lai
Owo ni o je, koni je agbado, oh-ohh
Aranbada laye
Owo nio je oh, owo ni o je oh-ohh

Imagine say na me get money pass
I go pay all lectures fees and put an end to ASUU strike
Imagine say I be babalawo
I go fight spiritual for Corona, make my people dey alright
T'enu ba je, oju a ti
Ohun t'owo ba sheti, ile lo ma gbe
Eni ba gbin gedu s'ojude mi
Adigun, o fe funmi ni iboji ni

Akuko baba mi kan lai lai
Owo ni o je, koni je agbado, oh-ohh
Akuko baba mi kan lai lai
Owo ni o je, koni je agbado, oh-ohh
Aranbada laye
Owo nio je oh, owo ni o je oh, oh-ohh

Lekan oh Akinyele (Akinyele)
Lekan, oloore mi ni
Lekan oh Akinyele (Akinyele)
Lekan, oloore mi ni
Egbon Femi Oko L'ere Agbe, gbogbo Akure
Loko', iwo l'egbon Femi Oko L'ere Agbe, Akure ni
Gentle, alashe G-Unit
Gentle, egbon Lekan Akinyele
Gentle, oko Abidemi
Gentle, gbogbo efon alaye
Lekan Akinyele, imule wo'le kanle
Lekan Akinyele, imule wo'le kanle
Wo'le kanle, wo'le kanle
Iwo loni ile, wo'le kanle
Eru o b'omo oloode, wo'le kanle
Eru o gbudo b'omo Ogbomojugun, wo'le kanle-e
(Olumix on the Mix)



Credits
Writer(s): Alexander Ajifolajifaola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link