Iwaju

Iwaju iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwájú laa máa máa lo
Want song, wants flavour
E maa ríran wò ti n ba k'orin
Mo rí èèmo l'agege, ajá w'ewu o roso

Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju iwaju
Iwaju laa máa máa lo

Enu eni laa fi ko meejè
Enu eni ní power
Give me more power, more more blessings
Ti n ba kankun wàá fí fún mi
Ibéèrè mí re o, je o leesi
Give me more power, more more blessings

Many wey you don bless, I follow them celebrate
Many wey you give power
Them misuse am we no dae

Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Laa máa máa lo

Aro wa ti weere l'aiye
Iwaju ni n máa má lo
Lókè, lókè looke ni n máa má ló
B'óta mi p'ogun, p'ogbon won lee lasan
Iwaju ní n máa má lo
Lókè, lókè looke ni n máa má ló
Iná tí ómó oko ya, l'ómo alè fí sun isu je
Lókè, lókè looke ni n máa má ló

Iwaju Iwajui
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Want song, wants flavour
E maa ríran wò ti n ba k'orin
Mo rí èèmó l'agege, ajá w'ewu o roso

Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo



Credits
Writer(s): Abiola Isaac Daramola, Doyinsola Joshua Adesanya, Alexander Ajifolajifaola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link