Mumi Debe

Báyé bá n ṣe tana di mi, Baba ma gbà
Báyé bá n so fò kò niṣo, Baba ma gbà
Kokoko lójú aiye le Baba yọ mi
Ṣanu mi eledami
Ko tun aiye mi ṣe
Mumi debe
Mumi debe OLUWA mumi debe
(Mumi de ibi Ayo mi)
Mumi debe OLUWA mumi debe
(Baba mumi debe)
Gba ko so aiye mi mo gbekele o
(Baye ba she tano di mi)
Ibi ayo aiye mi (Baba o)
Ibi ogo mi (Oluwa)
Aseda mi ma sai mumi debe

Mumi debe, Oluwa mumi debe (Fami lowo lo si be Baba)
Mumi debe, Oluwa mumi debe (Ere taja fi ogun odun sa)
Gbakoso aiye mi, mo gbẹkẹle ọ
Ibi ayo àiyé mi, ibi ògo mi
Asèdá mi, ma ṣai mú mi de'bẹ (ma ṣai mumi de'bẹ)

Ogún burú a lù ni pa Baba ma gbà
Èsù ròrò mbá aiye eni jẹ Bàbá ma gba o
Iya o tosí mi, ọlọrun mi gbà mí
Ojú rẹ lémi n wo o
Ṣe temi ni re (mumi de'bẹ)

Mumi de'bẹ Oluwa mumi de'bẹ (Baba mumi de'bẹ)
Mumi de'bẹ Oluwa mumi de'bẹ
Gbàkoso aiyé mi, mo gbẹkẹle o
Ibi ayọ aiye mi, ibi ògo mi (Baba ṣanu mi)
Asèdá mi, ma ṣai mumi de'bẹ

Báyé bá n ṣe tana di mi, Baba ma gbà
Báyé bá n so fò kò niṣo, Baba ma gbà
Kokoko lójú aiye le Baba yọ mi
Ṣanu mi eledami
Ko tun aiye mi ṣe

Mumi de'bẹ Oluwa mumi de'bẹ
Mumi de'bẹ Oluwa mumi de'bẹ
Gbàkoso aiyé mi, mo gbẹkẹle o
Ibi ayọ aiye mi, ibi ògo mi
Asèdá mi, ma ṣai mumi de'bẹ

Mumi de'bẹ Oluwa mumi de'bẹ (Baba mumi de'bẹ)
Mumi de'bẹ Oluwa mumi de'bẹ
Gbàkoso aiyé mi, mo gbẹkẹle o
Ibi ayọ aiye mi, ibi ògo mi
Asèdá mi, ma ṣai mumi de'bẹ



Credits
Writer(s): Patricia Temitope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link