Oruko Jesu

Orúkọ Jésù ní ìràpadà mí
Orúkọ Jésù ní iso àgbàrá mí
The name of Jesus sure inheritance
The name of Jesus is life and light

Call the name, call the name, Jesus
Call the name, call the name, Jesus
Call the name, call the name, Jesus
Call the name, call the name, Jesus

Orúkọ Jésù ní ìràpadà mí
Orúkọ Jésù ní ilésọ àgbàrá mí
The name of Jesus sure inheritance
The name of Jesus is life and light

Call the name, call the name, Jesus
Call the name, call the name, Jesus
Call the name, call the name, Jesus
Call the name, call the name, Jesus

His name is Light
Keeps the devil at bay
Full of power and grace

Ọpẹ́ẹ ní fún àwọn tí ko mọọ
Ìye ní fún àwọn to mọ, tọ pé orúkọ ná
E pe orúkọ

Call the name, call the name, Jesus
(Call the name) call the name, call the name, Jesus
(Call the name) call the name, call the name, Jesus
(The name of Jesus-) call the name, call the name, Jesus

His rock and shield
Refuge in every storm
Àgbàrá tọ ju àgbàrá lọ
Àpòrọ́ àrùn àti ikú
Ayérayé ní ìyè tọ wá nú orúkọ náà
Bẹẹni

Orúkọ Jésù ní ìràpadà mí (iràpadà lọ jẹ)
Orúkọ Jésù ní ilé ìso àgbàrá mí (ilé ìso àgbàrá níí)
The name of Jesus sure inheritance (orúkọ, orúkọ, orúkọ)
The name of Jesus is life and light (e pèé orúkọ)

(Call the name, call the name, Jesus) orúkọ tọ ń wọlé ikú, wọ ilé àrùn
(Call the name, call the name, Jesus) te bá pé, a dá yìn lòun
(Call the name, call the name, Jesus) e pé nígbà tọ wá ní tòsí óò
Lórí òun kòun te nfẹ, ẹ pé orúkọ náà

Orúkọ Jésù, ìgbàlà ńlá ló jé
Orúkọ tọ tóbi ju
Àṣírí ìjìnlẹ' níí
Orúkọ tọ mú òun gbogbo wá láti ipinleṣe o
Orúkọ ńlá

(Call the name, call the name, Jesus) ẹ pé orúkọ ọrọ
(Call the name, call the name, Jesus) oun lá fí da òun gbogbo
(Call the name, call the name Jesus) à tètèkọsẹ̀ lórúko náà
Òun lo ṣáájú dé kí òun gbogbo tó wá oo

Orúkọ Jésù
Atọna mí níí
Oko àt'ogún ìlú ìbílè mí
Orúkọ olùlàájá wá lọdọ Bàbá
Àfihàn ọ'rẹ' ọ'fẹ' fún àwa tọ gbagbọ

Call the name (call the name, call the name, Jesus)
He's the beginning and the end (call the name, call the name, Jesus)
Ò ṣáájú ọrun dé (call the name, call the name, Jesus)
O ṣáájú orun wa
Òun lọ kó àyè (call the name, call the name, Jesus)

Àwọn òungbogbo èyí táarí
Àti èyí t'aori, orúkọ yí lọ ko wọn
Epe oruko re (call the name, call the name, Jesus)
Aaa dáhùn
Epe oruko re ooo
Jigirin, a tètè kọsẹ̀

Orúkọ tọ ṣáájú dé
Òun ní ilẹ̀kùn wá
Sílè ògo
Òun ní kọ'kọ'rọ' tọ ṣílẹ̀kùn ògo fún wá
Òun ní ayérayé gbogbo ẹ'dá
Òun ní orúkọ tọ tóbi julo

The name of Jesus
The strong tower
Every knee must bow
Every tongue will confess that Jesus
Is the name that is above every other names



Credits
Writer(s): Tope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link